Search Header Logo

ATUNYEWO ISE

Authored by Cecilia Oguntimehin

World Languages

9th Grade

Used 5+ times

ATUNYEWO ISE
AI

AI Actions

Add similar questions

Adjust reading levels

Convert to real-world scenario

Translate activity

More...

    Content View

    Student View

40 questions

Show all answers

1.

MULTIPLE CHOICE QUESTION

1 min • 1 pt

Àwọn wo ni won ko àṣà ìwé kíkọ àti kíkà wá sí ilẹ̀ Yorùbá?

Òyìnbó ẹlẹ́sìn musulumi

Òyìnbó ẹlẹ́sìn kirisiti      

Òyìnbó Potogí

Awon elesin juu

2.

MULTIPLE CHOICE QUESTION

1 min • 1 pt

Ẹṣin wo ni o mú kíkọ àti kíkà iwe wá sí ilẹ̀ wa?

Iborisa

Musulumi  

Kirisiti

Imole

3.

MULTIPLE CHOICE QUESTION

1 min • 1 pt

  Ọmọ ìlú wo ni Samuel Àjàyí Crowther jẹ́?

Ondo

Benin

Ile-Ife

Oyo

4.

MULTIPLE CHOICE QUESTION

1 min • 1 pt

Kíni ìtumọ̀ ajinhinrere ni èdè gẹ̀ẹ́sì?

Elder

Evangelist

Chairman

Executive

5.

MULTIPLE CHOICE QUESTION

1 min • 1 pt

Odùduwà àti àwọn ènìyàn rẹ fì _____________ọjọ rìn láti Mẹkà dé Ìlú Ilé-Ifè.

aadorun

aadosan

aadota

ogorin

6.

MULTIPLE CHOICE QUESTION

1 min • 1 pt

___________ ni Odùduwà bi ní ìlú Ilé-Ifè.

Sango

Oranmiyan

Okanbi

Omonide

7.

MULTIPLE CHOICE QUESTION

1 min • 1 pt

Ọmọ mélòó ni Oranmiyan bi?

Mesan

Mefa

Meje

Meji

Access all questions and much more by creating a free account

Create resources

Host any resource

Get auto-graded reports

Google

Continue with Google

Email

Continue with Email

Microsoft

Continue with Microsoft

or continue with

Facebook

Facebook

Apple

Apple

Others

Others

Already have an account?