Search Header Logo

EYA ARA IFO YEAR 7B

Authored by Cecilia Oguntimehin

World Languages

7th Grade

Used 1+ times

EYA ARA IFO YEAR 7B
AI

AI Actions

Add similar questions

Adjust reading levels

Convert to real-world scenario

Translate activity

More...

    Content View

    Student View

11 questions

Show all answers

1.

MULTIPLE CHOICE QUESTION

1 min • 2 pts

Media Image

____________ àwọn ẹ̀yà  ara ti won n jumo sisẹ  papo láti  gbé  iro èdè  jáde  ni ẹnu .

silebu

alifabeeti

Eya ara ifo

ounje ile Yoruba

2.

MULTIPLE CHOICE QUESTION

1 min • 2 pts

Media Image

Awọn ẹ̀yà  ara ifo wa lati ori wa de __________ wa.

ikun

ese

apa

idodo

3.

MULTIPLE CHOICE QUESTION

1 min • 2 pts

Media Image

Awọn ẹ̀yà  ara ifo pin si ______________.

ona kan

ona merin

ona meji

ona meta

4.

MULTIPLE CHOICE QUESTION

1 min • 2 pts

Media Image

Awọn ẹ̀yà  ara ifo ti A LE fi oju ri ni a npe ni _______________________ ni ede Geesi.

non available organs of speech

available organs of speech

non-physical organs of speech

physical organs of speech

5.

MULTIPLE CHOICE QUESTION

1 min • 2 pts

Media Image

Awọn ẹ̀yà  ara ifo ti A KO LE fi oju ri ni a npe ni _______________________ ni ede Geesi.

non available organs of speech

available organs of speech

non-physical organs of speech

physical organs of speech

6.

MULTIPLE CHOICE QUESTION

1 min • 2 pts

Media Image

Edo-foro je okan lawa awon ẹ̀yà  ara ifo ti

a ko le fi oju ri

ti a nwo kedere

ti o wa ninu apo wa

ti a fi nse obe ata

7.

MULTIPLE CHOICE QUESTION

1 min • 2 pts

Media Image

__________ni àwọn ẹ̀yà ara-ifọ láti òkè tán-án-ná sí ẹnu tí wọ́n ń kópa nínú gbígbé ìró èdè jáde.

Asunsi

Afipe

Akanmole

ahunso

Access all questions and much more by creating a free account

Create resources

Host any resource

Get auto-graded reports

Google

Continue with Google

Email

Continue with Email

Microsoft

Continue with Microsoft

or continue with

Facebook

Facebook

Apple

Apple

Others

Others

Already have an account?