Search Header Logo

ISE SISE YEAR 8 BLUE & RED

Authored by Cecilia Oguntimehin

Other

11th Grade

Used 1+ times

ISE SISE YEAR 8 BLUE & RED
AI

AI Actions

Add similar questions

Adjust reading levels

Convert to real-world scenario

Translate activity

More...

    Content View

    Student View

10 questions

Show all answers

1.

OPEN ENDED QUESTION

5 sec • 10 pts

Ewo ni ORO ISE ninu awon gbolohun isale wonyii:      

Ọmọladé jẹ iresi lánàá ní ìlú Abẹ́òkúta.

Kolade ra ọkọ̀ ayokele ni ìlú òyìnbó.

Ọga ilé ìwé na Jóṣúà ní ijeta.

Mọ gbà Yẹ́misí ní abara to gbóná.

    Ìyá Òjó se ọbẹ̀ egusi.

Bàbá àgbà sáré lọ si ehinkule.

Ọrọ náà dùn mí lọpọlọpọ.

Olùkọ́ wa ṣẹ̀ṣẹ̀ dé láti ilé ìwòsàn ní ọṣẹ tó kọjá.

IOgbeni Faleke ṣe igbayawo ni ọdún tó kọjá.

    Maami ra aṣọ tuntun fún mi.

Evaluate responses using AI:

OFF

2.

OPEN ENDED QUESTION

5 sec • 10 pts

Fa ila si abe ORO ASOPO ninu awon gbolohun isale wonyii:      

Ìbùkún àti Ifeoluwa gba oro naa gbo.

    Daniel jẹun àmọ́ kò fo àbọ̀.

 Fopeyinmi oun Caritas lọ sí etí òkun náà fún igbafe.

Àwọn agbaboolu náà gbìyànjú ṣùgbọ́n omi pọ ju ọkà lọ.

   Ogbeni Wande-Káyọ̀dé fẹ́ràn lati jẹ iresi alata ṣùgbọ́n ko si owo rẹpẹtẹ lọ́wọ́ rẹ.

Evaluate responses using AI:

OFF

3.

OPEN ENDED QUESTION

5 sec • 10 pts

Fa ila si abe ORO ATOKUN ninu awon gbolohun isale wonyii:      

1.     Marzooq lọ si Ìbàdàn lánàá.

2.     Dare jẹun titi ti ìyá rẹ fi dé.

3.     Ọdọ bàbà àgbà ni gbogbo wọn lọ.

Evaluate responses using AI:

OFF

4.

OPEN ENDED QUESTION

5 sec • 10 pts

Kọ orin eremode kan tí o mọ silẹ.

_________________________________________

_________________________________________

_________________________________________

_________________________________________

_________________________________________

_________________________________________

Evaluate responses using AI:

OFF

5.

OPEN ENDED QUESTION

5 sec • 10 pts

Kọ àwọn ìsòrí ọrọ silẹ.

6.

OPEN ENDED QUESTION

5 sec • 10 pts

Lẹ́tà gbefe ni irúfẹ́ lẹ́tà ti a lè kọ sí ẹnì to sún mọ́ wa. Kọ àwọn márùn-ún tí a lè kọ lẹ́tà gbefe sí.

Evaluate responses using AI:

OFF

7.

OPEN ENDED QUESTION

5 sec • 10 pts

Kọ oṣù nínú ọdún silẹ ní èdè Yorùbá.

Evaluate responses using AI:

OFF

Access all questions and much more by creating a free account

Create resources

Host any resource

Get auto-graded reports

Google

Continue with Google

Email

Continue with Email

Classlink

Continue with Classlink

Clever

Continue with Clever

or continue with

Microsoft

Microsoft

Apple

Apple

Others

Others

Already have an account?