
Yoruba - Half Term ( Alpha term 2024/2025)
Authored by Beedel Brooke
Other
4th Grade

AI Actions
Add similar questions
Adjust reading levels
Convert to real-world scenario
Translate activity
More...
Content View
Student View
10 questions
Show all answers
1.
MULTIPLE CHOICE QUESTION
1 min • 2 pts
Alifabeeti melo lo wa ninu ede Yoruba ?
Marundinlogbon
Marunlelogbon
Marundinlogun
2.
MULTIPLE CHOICE QUESTION
1 min • 2 pts
Awon ti won wa lati idile onilu ni a n pe ni
Alawo
Onirin
Aayan
3.
MULTIPLE CHOICE QUESTION
1 min • 2 pts
Okan lara awon oruko eni ti o wa lati idile onilu ni
Ibironke
Ayanwole
Adeola
4.
MULTIPLE CHOICE QUESTION
1 min • 2 pts
Osu karun ninu odun ni a n pe ni
Owara
Ebibi
Ogun
5.
MULTIPLE CHOICE QUESTION
1 min • 2 pts
Ki ni 30 ni ede Yoruba ?
Mewa
Mokanla
Ogbon
6.
MULTIPLE CHOICE QUESTION
1 min • 2 pts
Erena je osu ni ede Yoruba
karun
keta
kewa
7.
MULTIPLE CHOICE QUESTION
1 min • 2 pts
Ilekun onigi ti awon gbenagbena maa n se eso si ni aye atijo ni
Aase
irin
Igbale
Access all questions and much more by creating a free account
Create resources
Host any resource
Get auto-graded reports

Continue with Google

Continue with Email

Continue with Classlink

Continue with Clever
or continue with

Microsoft
%20(1).png)
Apple
Others
Already have an account?