Search Header Logo

Yoruba

Authored by Tiwatayo Okungbure

Other

7th Grade

Used 1+ times

Yoruba
AI

AI Actions

Add similar questions

Adjust reading levels

Convert to real-world scenario

Translate activity

More...

    Content View

    Student View

10 questions

Show all answers

1.

MULTIPLE CHOICE QUESTION

30 sec • 1 pt

Kini a n pe awon ileke ti awon obinrin maa n fi si idi?

a) Yeri

b) Bebe idi

c) Ileke owo

d) Ileke orun

2.

MULTIPLE CHOICE QUESTION

30 sec • 1 pt

Tani eni ti o maa n fa ori awon okunrin ni ile Yoruba?

a) Onisona

b) Onigbajamo

c) Onila

d) Onibata

3.

MULTIPLE CHOICE QUESTION

30 sec • 1 pt

Kini oruko bata ti awon Yoruba maa n wo si ese?

a) Salubata

b) Kobo

c) Salu

d) Saluwo

4.

MULTIPLE CHOICE QUESTION

30 sec • 1 pt

Kini a n pe awon aworan ti a maa n ya si ara?

a) Ila

b) Laali

c) Ara finfin

d) Osun

5.

MULTIPLE CHOICE QUESTION

30 sec • 1 pt

Iru aroko wo ni a n fi n se apejuwe bi nnkan se ri?

a) Aroko oniroyin

b) Aroko alapejuwe

  • c) Aroko alalaye

d) Aroko alariyanjiyan

6.

MULTIPLE CHOICE QUESTION

30 sec • 1 pt

Ewo ninu awon asa yii ni o je asa oge sise?

a) Asa igbeyawo

b) Asa isomoloruko

c) Asa aso wiwo

d) Asa oku sisin

7.

MULTIPLE CHOICE QUESTION

30 sec • 1 pt

Kini ogun ni ede Yoruba?

a) Ookanla

b) Eewaa

c) Oogun

d) Ogbon

Access all questions and much more by creating a free account

Create resources

Host any resource

Get auto-graded reports

Google

Continue with Google

Email

Continue with Email

Classlink

Continue with Classlink

Clever

Continue with Clever

or continue with

Microsoft

Microsoft

Apple

Apple

Others

Others

Already have an account?