Search Header Logo

Àṣà Iranra-ẹni-lọ́wọ́ àti ìkíni

Authored by Awógbadé Bùsáyọ̀ Audu

World Languages

8th Grade

Used 3+ times

Àṣà Iranra-ẹni-lọ́wọ́ àti ìkíni
AI

AI Actions

Add similar questions

Adjust reading levels

Convert to real-world scenario

Translate activity

More...

    Content View

    Student View

10 questions

Show all answers

1.

MULTIPLE CHOICE QUESTION

30 sec • 1 pt

Àṣà iran-ara-eni-lówó tó ni i șe pèlú gbigba ilopo owó tí a yá èniyàn ni....

A. Sogůn-dogóji

Ọ̀wẹ̀

Arokodoko

Àáro

2.

MULTIPLE CHOICE QUESTION

30 sec • 1 pt

Asà iran-ara-eni-lówó wo ni kò pon dandan láti san padà?

Ọ̀wẹ̀

Arokodoko

Àáro

Fifidogo

3.

MULTIPLE CHOICE QUESTION

30 sec • 1 pt

A lè ran ara wa lówó nínú àwon isé bí ti;

Owó fífọ̀

Ilé kíkọ

Ọ̀rọ̀ sísọ

Aṣọ gbígbà

4.

MULTIPLE CHOICE QUESTION

30 sec • 1 pt

Irú àsà iran-ara-eni-lówó wo ni kí a fi omo eni sílè láti gba owó?

Ọ̀wẹ̀

Fífıdógò

Esùsú

ÀÁRÒ

5.

MULTIPLE CHOICE QUESTION

30 sec • 1 pt

Èwo nínú èyí ni àsà iran-ara-eni-lówó tó jẹ mó owó?

Àjọ

Àrokodóko

Àáró

Ộwè

6.

MULTIPLE CHOICE QUESTION

30 sec • 1 pt

Àwọn wo là n ki pe "Àrinpa Ògun o"? . B. Ode D. Apeja E. Eléran

Àgbẹ̀

Ọdẹ

Apẹja

Ẹlẹ́ran

7.

MULTIPLE CHOICE QUESTION

30 sec • 1 pt

Báwo la sé ń kí èniyàn ni iròlé? "E ku..

Àárọ̀

Ọ̀sán

Ìrọ̀lẹ́

Ìnáwó

Access all questions and much more by creating a free account

Create resources

Host any resource

Get auto-graded reports

Google

Continue with Google

Email

Continue with Email

Microsoft

Continue with Microsoft

or continue with

Facebook

Facebook

Apple

Apple

Others

Others

Already have an account?