NEW
Font size
WorksheetsYORUBA
Total questions: 10
Worksheet time: 5mins
Ewo ni kii n ise asa iranra-eni-lowo ninu awon iwonyi?
ole jija
Ajo dida
Arokodoko
Owe sise
option 1
Boluwatife je oro silebu meloo
Marun-un
mefa
merin
meta
option 1
Silebu ni oro ti o kere julo ti ........ le gbe jade ni e n kan soso
Eemi
Enu
Eyin
Oju
Option 1
Gbogbo alifabeeti ede Yoruba je
Ogbon
Meedogbon
Mejidinlogun
Merindinlogon
"I am going home" tumo si
Mo lo si ile
Mo n lo si ile
Mo fe lo si ile
Mo fe wa si ile
Option 2
Igbeyawo je adehun pataki laarin.......... ati........ lati jo ma gbe po bi Oko ati Aya.
Omode ati Okunrin
Obinrin ati Obinrin
Okunrin ati Obinrin
Okunrin ati Agbalagba
Option 3
Ara awon ohun elo fun idana Igbeyo ni ile Yoruba ni
Oba ati Ada
Kumo ati odo
Isu ati Apoti aso
Omi ati Ose
Option 3
........ ni eya Yoruba ti won feran “gaari ati eja’’ bii ounje
Ilorin
Ondo
Ijebu
Eko
Option 3
Iyan ati isu je ounje awon...........
Eko
Ekiti
Oyo
Ilorin
Option 2
’Safe journey’ tumo si
Odabo
Oko Arifo
Ekabo
Ekasan
Option 2
