NEW
Font size
WorksheetsYORUBA
Total questions: 60
Worksheet time: 30mins
Orisi aroko to je mo ilani-loye ni aroko
Asariyanjiyan
Aseroyin
Onisongbesi
Ajemo isipaya
option 1
“Owo ko niran” je mo ori-oro fun aroko
Asapejuwe
Asariyanjiya
onileta
Aroso
option 1
“Ile-iwe mi” je aroko
Oniroyin
Asapejuwe
Onisongbesi
Alalaye
option 2
Ise Oluko wulo ju ise Agbe lo je apere aroko
Alalaye
Alariyanjiyan
leta
Asapejuwe
option 2
Adiresi meloo ni leta gbefe maa n ni?
meta
meji
eyokan
merin
option 3
Irufe leta ti a ko si ore wa ji apere leta
Gbefe
Aigbefe
Aroko
Oniroyin
option 1
Iro ti a pe ti ko si idiwo fun emi ni_________
silebu
faweli
ede
konsonanti
option 2
Ise wo ni Agba se ninu gbolohun yii “iya Agba ro Amala gbona
Abo
Oluwa
Eyan
Aponle
option 2
Opomulero ninu gbolohun ni oro
Oruko
Aponle
Asopo
Ise
option 4
Awon ti o sise ilu lilu ni ile Yoruba ni a n pe ni_________
Ode
Olode
Aayan
Oni sona
option 3
Faweli aranmupe meloo ni o wa ninu ede Yoruba?
Merin
Meje
Meta
Marun-un
option 4
Ipin-si-silebu Alapansanpa ni
Marun-un
Merin
Mefa
Meje
option 1
Ninu onka Yoruba ookanlelogun je_________
33
32
21
22
option 3
Ona meloo ni ale pin faweli ede Yoruba si
meta
merin
marun-un
meji
option 4
Oruko ti Yoruba n pe abiku ni okan ninu awon wonyii
Fijabi
Odewale
Durotimi
Oyegbami
option 3
Bawo ni a se seda oro yii aisun?
ais + un
ai + sun
a + isun
aisun
option 2
Bawo ni a se seda idajo?
Idajo
ida + do
ida + do
I + da + jo
option 4
Oruko amutorunwa ni
Kehinde
Tunde
Gbolade
Oyinloye
option 1
Itumo akanlo ede won yii “igbeese le”
bimo
duro
ibinu
pase
option 4
Diwo dise tumo si
ki obinrin sanra
ki obinrin sun
Ki obinrin bimo
Ki obinrin loyun
option 4
Gbo agboya tumo sii (a)
Omo rere
aigboran
gboro si obi
Fi gbigbo se alaigbo
option 4
Apapo alifabeeti ede Yoruba je
Meedogbon
Merindinlogun
Metalelogun
metalelogun
option 1
Ona meloo ni iro ailifabeeti ede Yoruba pin si
mejo
marun-un
merin
meji
option 4
Ninu “Emi ni oga awon omo naa”, isori oro wo ni ‘Emi’?
Oro-Aropo Afarajoruko
Oro- Apejuwe
Oro- Aponle
Oro-ise
option 1
Oruko awon ti won se itoju alaboyun lo igba lode ni?
awako
oogun
ile iwosan
dokita
option 4
“Olu alagidi lu omo pa”. Apola ise inu gbolohun yii ni
lu omo
Olu lu omo pa
Alagidi lu omo pa
lu omo
option 2
Ewo lo ni awe-gbolohun asapejuwe ninu?
Ile ti mo re ga
ile ki I ku
Won ni awon n bo
Ile baba mi tobi
option 4
“Fori oka homu” tumo si pe eniyan
Tun iwa ara re se
se n kan to ju agbara eniyan lo
Fowo ho ori
Ko ire mora
option 2
Igba ninu onka ede Yoruba je
100
200
300
400
option 2
400 je ............... ninu onak Yoruba
Egbeta
Irinwo
igba
Ogorun
option 2
He was once the owner of this house (a)
Oun ni o ni ile yii nigba kan ri
Ile yii nikan ni o ni
O fera ile yii nigba kan
Oun nikan ni o ni ile yi
option 1
The two friends seem to be very intimate
O dabi pe kori-kosun ni awon ore mejeeji
Awon ore mejeeji nifee ara won
Awon ore mejeeji je kori-kosun ara won
O dabi pe ore mejeeji gbadun ara won
option 1
He lured her to divorce her husband
O pase fun un lati fi oko re sile
O tan an lati ko oko re sile
O fi I fun oko meeran
O le e kuro nile oko re
option 2
He ran to see the old woman
O sare si iya
O mo ere sa
O sare si iya gba na
O sare lati ri iya agba na
option 4
1. Konsonanti afetepe aranmupe ni (a) b (b) f (c) j (d) m (e) w
W
M
J
F
OPTION 2
Konsonanti ti o wa ninu ede Yoruba je (a)
Mejidinlogbon
meejidinlogun
mejIlelogun
marun-un
option 2
‘Ojo lo ra bata ni ilu Eko’ Toka si oro oruko inu gbolohun yii
Eko
Ojo
NI
Ilu
option 2
Ewo ni kii se oro asopo ninu awon won yii
yala
ati
aya
sugbon
option 3
Akoto ‘Ilesha’ ni
Lesa
Ilesaa
Ilesha
Ilesa
option 4
Ege oro ti eemi le gbe jade ni e n kan soo a n pe ni
faweli
silebu
konsonanti
ede
option 2
Leta ti a ko lati wase ni leta...............
Gbefe
ile-ise
Aigbefe
Oniroyin
option 3
Leta ti a ko lati wase ni leta...............
Gbefe
ile-ise
Aigbefe
Oniroyin
option 3
Ewo ni ori-oro to je mo aroko asapejuwe?
Ile-oba ilu mi
Jagunjagun ori-omi
Eso Apaniyan
Ogun ilu
option 1
Aroko "omo wulo ju owo lo" je mo aroko................
Oniroyin
Alalaye
Alariiyanjiyan
Asapejuwe
option 3
Iru leta wo lo maa n fi aaye sile fun ikini?
Leta aigbefe
Leta gbefe
leta aroko
Leta si oge
option 2
Olu broke sola's heart means
Olu fo okan sola
Olu ba Sola ninu je
Olu ja Sola laya
Olu da inu Sola ru
option 2
They might have started the meeting. means
Won ti fe bere ipade naa
Won ti le bere ipade naa
Won a ti bere ipade naa
Won maa bere ipade naa
option 2
Let us go hunting. means
E je ki a lo paran
A maa lo peran
A le lo peran
E je ki a maa peran
option 1
The student was commended for his brilliance
Akekoo naa gboriyan fun ijafafa re
Akekoo naa gboriyin fun ori pipe re
Akekoo naa gboriyin fun aigba gbere re
Akekoo naa gboriyin fun akitiyan re
option 2
Langbe ori ebe je ipolowo
iresi
isu
ila
agbado
option 4
Aduda wo lo ya faweli aranupe soto si faweli airanmupe?
Ipo ti ete wa
giga ahon
fife tan-an-na
ipo ti afase wa
option 1
Ewo ni gbolohun ase?
O pari
Ade ti jeun
Mo fe di dokita
Wa nibi
option 4
Ninu "Olu ba egbon re ja", 'ba... ja" je
oro ise
oro oruko
oro apejuwe
oro aponle
option 1
Oro aropo afarajoruko ni...............
emi
won
wa
yin
option 1
Gbogbo awon wonyii ni ona ti a n gba paroko AYAFI
tabili
enu
imu
oju
Alifabeeti keji ninu ede Yoruba ni
A
U
D
B
Omo ti iwa re dara ni awujo ni Yoruba n pe ni........
Omo bibi
Omoluabi
Omokomo
Omo mi
Mejilelogorin je............. ninu ede Yoruba
71
82
99
91
Metadinlogbon je.......... ninu ede Yoruba
38
50
27
23
Orisii ami ohun ede Yoruba ni..............
merin
meta
metamarun-un
mefa
