NEW
Font size
WorksheetsYORUBA LANGUAGE
Total questions: 61
Worksheet time: 31mins
............ni awon eya ara ti a nlo fun gbigbe iro ede jade?
awon isori oro
awon eya ara ifo
awon alifabeeti
awon nomba.
option 2
1. Eya ara ifo ti a le fi oju ri niwonyi, ayafi
ahon
komookun
ede
eyin
option 3
Orisii ami ohun inu ede Yoruba je
mejila
merin
mefa
meta
option 3
‘’19” ni onka Yoruba je
ogun
ogbon
eejidinlogun
ookandinlogun
option 4
ege oro ti eemi le gbe jade ni ekan soso ni.............
silebu
faweli
fuloloji
ede
option 1
Silebu meloo ni o wa ninu APONBEPORE
mefa
merin
marun-un
meta
option 3
kabiyesi je oro silebu meloo
marun
merin
meta
mefa
option 2
Orisii litireso ede Yoruba je
meji
meta
merin
marun
option 1
ona ti a n gba gbe iro okan wa jade fun e lo miran ni a n pe ni
litireso
ede
asa
oro
option 2
Iwa ati isesi awon eniyan ni awon Yoruba n pe ni
Asa
ogbon
litireso
ede
option 1
Ara iwulo ede ni iwonyi ayafi
Oro siso
Orin kiko
iwure ati adura
eebu ati ija
option 4
Leta to bere alifabeeti ede Yoruba ni
A
B
D
GBE
option 1
Leta yii lo pari alifabeeti ede Yoruba
w
y
p
r
option 2
Aadota ni onka ede Yoruba ni..........
45
55
50
51
option 3
Eya litireso alohun ede Yoruba niyi, ayafi
ajemo oro geere
ajemowaale
ajemotan aroso
ajemayeye
option 4
Litireso alohun ti omidan-binrin ti n mura ile oko maa n lo lati dagbere ni agbegbe Oyo ni
rara
obitun
biripo
ekun- iyawo
option 4
Awon ........... ni won ni Dadakuada ni ile Yoruba
eko
yewa
oyo
igbomina
option 4
Ewo ni kii se oro onisilebu kan?
wa
awa
ebi
sunre
option 1
Ewi omode ni awon orin iwerende ti won maa n ko ni akoko...........
aaro
osan
irole
ale
option 3
Oro ti aya lati inu ede kan si ede miran ni............
oro ayalo
silebu
faweli
ede
option 1
Teacher ni ede Yoruba ni
oluko
omode
ile-iwe
omode
option 1
bread ni ede Yoruba ni
buredi
bugan
ounje
omi
option 1
Ona miran ti a le gba ba eniyan soro la ilo enu ni........
Pipa aroko
Sisa are
jijeun
nina owo
option 1
Ara iwa to ye omoluabi ni................
otito
ole
ija
agidi
option 1
Omoluabi ni omo ti iwa ati ise re dara lawujo?
beeko
beeni
koyemi
rara
option 2
Orisii leta meloo lowa ninu ede Yoruba
meta
merin
meji
marun
option 3
Irufe leta e ko si eni mimo wa ni
leta gbefe
leta aigbafe
leta oniroyin
leta ona
option 1
Irufe leta ti a ko si eni to wa ni ipo jija ni
leta gbefe
leta aigbafe
leta oniroyin
leta rere
option 2
irufe leta ti o ni adiresi kan ni
leta aigbefe
leta rere
leta gbefe
leta rere
option 3
Ki awon oyinbo alawo funfun to mu esin ajeji wa ni awon Yoruba ti ni igbagbo ninu .............
oduduwa
olodumare
orunmila
ogun
option 2
igbese akoko ninu leta gbefe ni ----?
ipari leta
akole leta
adiresi kiko
deeti kiko
option 3
Good morning nile Yoruba ni
kaaaro
ku ise
ku ile
ekasan
option 1
‘Good night’ tumo si
ekale
odaro
ekasan
ekurole
‘I am going home’ tumo si
mo wa si ile
mo mo ile
mo n lo si ile
mo fe wa si ile
option 3
Okandinladota ni onka Yoruba ni.........
59
49
43
51
option 2
eetalelogoji ni onka ede Yoruba
44
43
42
41
option 2
'i am coming' tumo si
Mo n bo
Mo fe ma bo
Mo n lo
Mo fe wa
option 1
Gbogbo alifabeeti ede Yoruba je
merindinlogbon
meedogbon
metadinlogbon
mejilelogun
option 2
Faweli ede Yoruba pin si ona..............
meta
meji
merin
marun
option 2
Apeere fawewli aranmupe ni
a
e
i
nu
option 4
1. Eya ara ifo ti a le fi oju ri niwonyi, ayafi
ahon
komookun
ede
eyin
option 3
Leta ti a ko lati wase ni leta...........
Gbefe
Ile-ise
Aigbefe
Oniroyin
option 3
Iru leat wo lo maa n fi aaye sile fun ikini?
Leta aigbefe
Leta aroko
Leta gbefe
Leta si oge
option 3
Apapo konsonanti Yoruba je...........
mewaa
mejidinlogun
metadinlogun
merindinlogun
option 2
Okan lara eya ara ipe yii je afipe Akan mole.
eyin Oke
Iwaju ahon
Edoforo
Ete isale
option 4
Ewo ni faweeli ninu awon won yii
b
e
j
f
option 2
Ona meji pataki ti a le pin faweeli ede Yoruba si ni.....
Aranmupe ati Ayanupe
Aranmupe ati Airanmupe
Airanmupe ati Aiyanupe
Aranmupe ati Afetepe
option 2
Bawo ni ete se maa n ri bi a ba pe /O/
Roboto
Perese
Lila
Didipo
Bawo ni ete se maa n ri bi a ba pe /O/
Roboto
Perese
Lila
Didipo
Faweeli ti kii bere oro ninu ede Yoruba ni............
e
o
a
u
option 4
Iya je eba tutu "eba-tutu" je...............
apola
ise
apejuwe
oruko
option 3
Aso dudu ni oga mi wo, dudu ninu gbolohun yii je...............
apola
ise
apejuwe
oruko
option 3
Dada lo si oja sugbon ko ri eja ra. Oro asopo ninu gbolohun yii ni..............
eja
dada
oja
sugbon
option 4
Ile mefa ni baba mi ko. mefa ninu gbolohun yii je eyan............
asonka
ajoruko
asapejuwe
asafihan
option 3
Baba ko ile "ko" ninu gbolohun yii je................
oro oruko
oro ise
oro eyan
oro atokun
option 2
Bolu lo si Oyo. Oro-oruko ninu gbolohun yii ni...............
Bolu ati Oyo
lo si
Bolu ati lo
si Oyo
option 1
Kin ni Nomba to duro fun "metalelogun"
23
33
34
31
option 1
Opomulero inu gbolohun je............
oro-ise
oro oruko
afomo-ibere
afomo-eyin
option 1
Omo ti ko ni obi ni a n pe ni.............
omo olomo
omo orukan
omo rere
omo alagbato
option 2
Oruko oye oba ilu ile-ife ni........
Ooni
Alake
Olomuo
Elerin
option 1
Eya ara akanmole ti a fi n pe iro ni....................
ete isale
eyin isale
aarin ahon
eyin oke
option 1
