wayground logo

Free Printable Worksheets

NEW

Font size

S
M
L
XL
Worksheets

Nigerian Language (YORUBA)

Total questions: 10

Worksheet time: 5mins

Name
Class
Date
1.

Ami ohun meloo lo wa ninu ede Yoruba

a)

merin

b)

meta

c)

eyo kan

d)

mefa

2.

Eya ara ifo ti a le foju ri ni ...........

a)

edoforo

b)

komookun

c)

ete

d)

efonha

3.

Iro faweli ti kii bere oro ni ede Yoruba ni ........

a)

/e/

b)

/a/

c)

/u/

d)

/i/

4.

Iro konsonanti meloo lo wa ninu ede Yoruba ?

a)

mejidinlogun

b)

marundinlogbon

c)

metadinlogun

d)

ogbon

5.

Pin oro yii si silebu 'Alayinlohun'

a)

A/loy/in/loh/un

b)

A/lo/yin/lo/hun

c)

A/loyin/lo/hun

d)

Al/oy/i/n/loh/u/n

6.

Oro to n so isele inu gbologun ni........

a)

oro oruko

b)

oro ise

c)

oro eyan

d)

oro ede

7.

Iru aroko wo ni a ti maa n ri ikini ibere?

a)

Leta

b)

Alapejuwe

c)

Oniroyin

d)

Alariiyanjiyan

8.

Pari owe yii, "Ile oba to jo, ........"

a)

o po pupo

b)

ko see fi enu so

c)

ewa lo bu si

d)

ko se e tun ko

9.

Bawo ni a se seda oro yii; "Imokimo"

a)

afomo ibere

b)

afomo aarin

c)

apetunpe elebe

d)

apetunpe kikun

10.

Ninu iwe "Ma dan an wo", ta ni o je Oba leyin ti Oba Adebola waja?

a)

Adegorioye

b)

Adeola

c)

Adegun

d)

Adifala