WorksheetsAja ati Ijapa
Total questions: 10
Worksheet time: 9mins
Name
Class
Date
1.
Awọn ẹranko wo ni o wa ninu itan aja ati ijapa?
a)
Dog and Lion
b)
Tortoise and Cat
c)
Squirrel and Tortoise
d)
Dog and Tortoise
2.
Ijapa ati aja lọ si (a) .
3.
Kini wọn ṣe ni Oko naa?
a)
jẹun
b)
ṣe'rẹ
c)
ji iṣu
d)
jo
4.
Aja mu iṣu _________
a)
pupọ
b)
niwọnba
c)
dudu
d)
gaan
5.
Ijapa ko iṣu _______.
a)
di ẹ
b)
pupọ
c)
niwọnba
d)
rẹgi
6.
Ni bo ni Ijapa ko iṣu to ko si?
a)
inu apo
b)
inu abọ
c)
inu awo
d)
inu apẹẹrẹ
7.
Kilode ti ijapa ni lo iranlọwọ aja?
4 lines
8.
Tani oloko mu?
a)
adiyẹ
b)
ijapa
c)
aja
d)
tolotolo
9.
Kini Oloko ṣe fun aja?
a)
o sọ di ẹran isin
b)
o pa jẹ
c)
o patewọ fun
d)
o ba ja
10.
Pari orin yi - Aja (a) ran mi l'eru, fẹrẹkufẹ.
100 %
