WorksheetsKILAASI EDE YORUBA
Total questions: 17
Worksheet time: 11mins
Ewo ni kii se ojo ose ni ede yoruba (which is not part of the days of the week in Yoruba)
Aiku
Aje
Ojoru
owewe
Abameeta
Ewo ninu ojo ose Yoruba lo tele ara won (tick the days of the week in correct order)
Aiku, Aje, Isegun, Ojoru, Ojobo, Eti, Abameeta
Aje, Abameeta, Ojoru, Eti, Aiku, Ojobo, Isegun
Abameeta, Aje, Ojoru, Eti, Isegun, Aiku, Ojobo,
Aje, Aiku, Isegun, Ojobo, Ojoru, Eti, Abameeta
Isegun means what in English------
Monday
Tuesday
Wednesday
Thursday
Ewo ni kii se faweli ede yoruba (which is not a vowel sound)----
A
E
I
M
Bawo a se n ki eniyan ni osan-----
E kaaro
E ku irole
Ekaasan
Ekaale
Bawo ni means-----
Where are you going to
How are you
How old are you
I am fine
Translate to Yoruba: I want to eat
(a)
Oro oruko (noun) je oruko eniyan, eranko, ibikan ati nkan. ewo ni oruko eniyan----
Adiye
Aja
Moyosore
Aguntan
Ewo apeere oro ise(verb)------
Tade
Amerika
Je
Tabili
Ko Alifabeeti ede Yoruba mefa akoko (Write the first six Yoruba alphabet)
(a)
Ko onka ede yoruba mefa akoko
(a)
Dahun Ibeere yii. Kini Oruko re (a)
Good bye means
(a)
Kini thirty ni Figo
meewa
mejila
ogbon
ogoji
Kini aropo mejila ati meewa
Ogbon
ogoji
igba
mejilelogun
Kini ayokuro ogun ati meewa
meewa
ogun
meji
merin
Kini apeere ibikan (place) ninu oro oruko
Abuja
Adetola
Igi
Pali
