wayground logo

Free Printable Worksheets

Font size

S
M
L
XL
Worksheets

Yoruba language online class test

Total questions: 10

Worksheet time: 5mins

Name
Class
Date
1.

Ìró leta wo ni o bẹrẹ orúkọ nnkan ti o wa nínú àwòrán yìí.?

What letter start the name of this object ?

a)

A a

b)

B b

c)

E e

d)

F f

2.

Ìró leta wo ni o bẹrẹ orúkọ nnkan ti o wa nínú àwòrán yìí?

What letter start the name of the object here.?

a)

G g

b)

B b

c)

D d

d)

E e

3.

Kin ni orúkọ awọ yìí ni ede Yoruba?

What colour is this in Yoruba?

a)

Awọ dudu

b)

Awọ funfun

c)

Awọ pupa

d)

Awọ bulu

4.

Kin ni a n pe ohun ti o wa nínú àwòrán yìí?

What do we call this object in Yoruba Language?

a)

Aga

b)

Tábìlì

c)

Abọ

d)

Omi

5.

Kin ni à ń pe awọ yìí ní èdè Yorùbá?

What colour is this in Yoruba Language?

a)

Awọ ewe

b)

Awọ dudu

c)

Awọ funfun

d)

Awọ aro

6.

Kín ni à ń pe ohun èlò yìí ní èdè Yorùbá?

What is the name of this object in Yoruba Language?

a)

Ṣíbí

b)

Abọ

c)

Ike

d)

Kọọbu

7.

Ka awọn ohun elo yìí kì o sọ onka tí ó jẹ.

Count this object and write out the number in Yoruba.

(a)  

8.

Gẹgẹ bí onka ede Yoruba, nọ́mbà wo ló tẹlẹ Eeji?

In Yoruba number, what number is next after 2?

a)

Ookan

b)

Ààrùn-un

c)

Ẹeta

d)

Eeje

9.

Bawo ni a ṣe n ki eniyan ni àárọ̀?

How do we greet people in the morning?

a)

Ẹ káàárọ̀

b)

Ẹ káàsán

c)

Ẹ kúùrọ̀lẹ́

d)

Ẹ káalẹ́

10.

Ba wo ni a ṣe ń kí ènìyàn ní aalẹ́?

How do we greet people at night?

a)

Ẹ káàárọ̀

b)

Ẹ káàsán

c)

Ẹ kúúrọ̀lẹ́

d)

Ẹ káalẹ́