Wayground logo

Free Printable Worksheets

Font size

S
M
L
XL
Worksheets

Ọrọ Iṣe - Verbs

Total questions: 10

Worksheet time: 19mins

Name
Class
Date
1.

Bawo ni a ṣe maa n sọ 'I will' ni ede Yoruba?

4 lines
2.

kini itumo - Maa gba aṣọ mi

a)

I have collected my cloth

b)

I want to collect my cloth

c)

I must collect my cloth

d)

I will collect my cloth

3.

Sọ awọn ọrọ iṣe mẹta ti a le lo fun iṣẹ - Metion three verbs that can be used for work

4 lines
4.

Play is --------------- in Yoruba?

4 lines
5.

Kini itumo - I have a lot of money.

a)

Mi o ni owo

b)

Mo ni owo

c)

Mo ni owo pupọ

d)

Mo fẹ owo pupọ

6.

"Mi o ti ri ọmọ mi fun osu mẹjọ" tu mo si..........

a)

I have not seen my child for eight days

b)

I have not seen my child for eight months

c)

I did not seen my child for eight years

d)

I have seen my child for eight years

7.

Ya aworan iya ti o n gbe ọmọ ẹ.

(draw a pictur of a mother carrying her child).

8.

So 'I want to play with my child but I have to read a book' ni ede Yoruba

4 lines
9.

Mo fẹran ki ma ________ ọgẹdẹ ti mo __________ ati iyi ti mo _____________

(a)  

10.

Mo gbodo sun ni ago meji tumo si (a)