wayground logo

Free Printable Worksheets

Font size

S
M
L
XL
Worksheets

Yoruba Year 3 2024 First Term

Total questions: 10

Worksheet time: 12mins

Name
Class
Date
1.

Ki ni ojo ti a n pe Sunday ni ede Yoruba?

a)

Ojo Aiku

b)

Ojo Isegun

c)

Ojo Aje

2.

Alfabeeti meloo lo wa ninu ede yoruba

a)

24

b)

25

c)

26

3.

Ojo Aje ni ojo to a ma lo si_______

a)

Ile josi

b)

Ile-iwe

c)

Moshalasi

4.

Ki ni a pe aworan yii ni ede yoruba?

(a)  

5.

Ewo ni ki i se leta Yoruba ninu awon wonyi

a)

W

b)

B

c)

C

6.

Ose ni a n pe ni

a)

Month

b)

Week

c)

Year

7.

Saturday ni a n pe ni (a)  

8.

Awon ojo meloo lo wa ninu ose?

a)

Mefa (6)

b)

Mesan-an (9)

c)

Meje (7)

9.

Ya, Fila?

10.

Ki ni a n pe July ni ede yoruba?

(a)