wayground logo

Free Printable Worksheets

Font size

S
M
L
XL
Worksheets

Abdussalam

Total questions: 32

Worksheet time: 27mins

Name
Class
Date
1.

Bawo ni aṣe ma n ki ara wa ni ọsan

a)

Ẹkaarọ

b)

Ẹkasan

c)

Eku irọlẹ

d)

Ẹkaalẹ

2.

Alifabeeti ede yoruba wo ni ko sí nínú èdè Yorùbá?

a)

B

b)

F

c)

GB

d)

Z

3.

Àkàwé ede yoruba wo niyi?

a)

Jigi

b)

Jagunjagun

c)

Alapata

d)

Gele

4.

Alifabeeti melo lo wani ede yoruba?

a)

25

b)

26

c)

30

d)

32

5.

Àkàwé wo ni yi?

a)

Jibi

b)

Ṣibi

c)

Ikọkọ

d)

Amala

6.

Bawo ni aṣe ma n ki ara wa ni alẹ?

a)

Ẹkaalẹ

b)

Ẹkaasan

c)

Ẹku irole

d)

Ẹkaaro

7.

Ọmọ ọdún melọ ni ẹ

a)

Eeji

b)

Ẹẹta

c)

Aarun

d)

Ẹẹjọ

8.

Onka èdè Yorùbá wo ni yii?

a)

Oorun

b)

Ẹẹta

c)

Aarun

d)

Eeji

9.

Kini aropọ yi ma fún wa?

a)

Okanla

b)

Ẹerin

c)

Ẹeta

d)

Eeje

10.

Onka èdè Yorùbá wo ni yii?

a)

Ẹẹfa

b)

Eeji

c)

Okan

d)

Ẹẹta

11.

Onka èdè Yorùbá wo lo tẹle eeje

a)

Ẹẹfa

b)

Ẹẹsan

c)

Ẹẹjọ

d)

Eewa

12.

Àkàwé wo re?

a)

Kọkọrọ

b)

Pẹpẹyẹ

c)

Tabili

d)

Gbegiri

13.

Onka èdè Yorùbá wo lo tẹle Ààrùn?

a)

Ẹẹrin

b)

Ẹẹfa

c)

Ẹẹta

d)

Okan

14.

Ṣe ayọkuro onka èdè Yorùbá yi

a)

Eeje

b)

Okan

c)

Ẹẹsan

d)

Ẹẹjọ

15.

Alifabeeti ede yoruba wo ni ko sí nínú Alifabeeti ede yoruba?

a)

CH

b)

A

c)

H

d)

K

16.

Àkàwé ede yoruba wo rẹ

a)

Aja

b)

Rakunmi

c)

Ẹṣín

d)

Ejo

17.

Onka èdè Yorùbá wo re?

a)

Aarun

b)

Ẹẹwa

c)

Okanla

d)

Ejila

18.

Aropọ onka yi a fún wa ni kini?

a)

Eejila

b)

Ẹẹtala

c)

Eeji

19.

Alifabeeti ede yoruba wo lati le ri àkàwé yìí?

a)

O

b)

B

c)

E

d)

U

20.

Àkàwé wo ni yi?

a)

Aga

b)

Yanmuyanmu

c)

Tabili

21.

Ka onka èdè Yorùbá lati ọkan de ẹẹwa

4 lines
22.

Kọ orin ọsẹ inu èdè Yorùbá

4 lines
23.

Fi ọwọ rẹ juwe ẹnu, eti, ẹsẹ

4 lines
24.

Ṣe àpèjúwe bí a ṣe n ki ara wa ni alẹ

4 lines
25.

Bawo ni aṣe n sọ NO ni ede yoruba?

4 lines
26.

Kini itumọ akẹ́kọ̀ọ́ ati olùkọ

4 lines
27.

Kọorin ji ko rorin

4 lines
28.

Bawo ni aṣe n ki mummy ati daddy ni arọ?

4 lines
29.

Sọ àkàwé meta ti o mọ fún alifabeeti B

4 lines
30.

Daruko eranko maarun ti o mo

4 lines
31.

Daruko eranko ti o mo?

4 lines
32.

Daruko eranko ti o mo?

4 lines