Wayground logo

Free Printable Worksheets

Font size

S
M
L
XL
Worksheets

Abdussalam

Total questions: 30

Worksheet time: 38mins

Name
Class
Date
1.

Kini oun èlò inule yíi?

a)

Kabinẹẹti

b)

Tabili

c)

Aga

d)

Pako

2.

Bawo ni a ṣe n sọ "I" ni ede yoruba?

a)

Oun

b)

Mo

c)

Iwọ

d)

Awọn

3.

Kini Rice ni èdè Yorùbá?

a)

Iṣu

b)

Àgbàdo

c)

Irẹsi

d)

Eba

4.

Abdullah fẹ --- sí ori ibusun

a)

Fọ

b)

Se

c)

Ra

d)

Sun

5.

Oun elo inule wọ ni a má n Fi jeun?

a)

Ẹro a mu nkan tutu

b)

Aga ati ibusun

c)

Sibi ati kabinẹẹti

d)

Abọ ati ṣibi

6.

Kini nkan ti a n Fi rorin

a)

Abọ

b)

Ṣibi

c)

Ifọyin

d)

Ata gungun

7.

Bawo ni a ṣe n ki ara wa ni alẹ?

a)

Ẹkaasan

b)

Ẹekalẹ

c)

Ẹkaabọ

d)

Ẹkaarọ

8.

Akawe ede yoruba wò ni yíí?

a)

Eti

b)

Ẹnu

c)

Ete

d)

Aọn

9.

Gbogbo nkan wọn yí ni òun elo inule ayafi?

a)

Iyepe

b)

Ikoko

c)

Abọ

d)

Kabinẹẹti

10.

Mummy --- aṣọ fún Abdussalam

a)

Jẹ

b)

Fo

c)

Mu

d)

Ra

11.

Oun èlò inule Re wò ni yíí?

a)

Ikolẹ

b)

Igbalẹ

c)

Tabili

d)

Ṣibi

12.

Ni bo ni o ma n sun sí?

a)

Aga

b)

Tabili

c)

Ibusun

d)

Ikoko

13.

Oun elo inule wọ rè?

a)

Ida

b)

Ọbẹ

c)

Igi

d)

Tabili

14.

A má n mu omi?

a)

Raara

b)

Bẹẹni

c)

Mi o mọ

15.

Bawo ni a ṣe n sọ "WE" Ni ede yoruba?

a)

Awa

b)

Mo

c)

Ò

d)

Oun

16.

Kini itumo "FẸ"?

a)

To have

b)

To walk

c)

To want

d)

To buy

17.

Kini itumọ "TO COME " ni ede yoruba?

a)

Fẹ

b)

Mu

c)

Jẹ

d)

Wa

18.

Kini aworan yii tọka sí?

a)

Sun Aṣọ

b)

Wa Aṣọ

c)

Fọ Aṣọ

19.

Kini a má n Fi igbalẹ ṣe

a)

A n Fi gba idọti

b)

A n Fi duro

c)

A n Fi kì joko

20.

Ibrahim fẹ ---si ìbi yìí

a)

N

b)

Wa

c)

Mu

d)

Ni

21.

Sọ awọn ọrọ yí ni ede yoruba

1). I want to dance

4 lines
22.

Darukọ oun èlò meerin ti o mọ

4 lines
23.

Kọ orin iya ni wura ni ede yoruba

4 lines
24.

Nibo lati lé ba Abọ, ṣibi, ikoko, ati obe padẹ ni inú ile

4 lines
25.

Sọ awọn ọrọ yí ni ede yoruba

He wants to jump

4 lines
26.

Sọ awọn ọrọ wọnyí ni ede yoruba

6) We dance

4 lines
27.

Sọ awọn ọrọ wọnyí ni ede yoruba

I want to drink water

4 lines
28.

Ja onka èdè Yorùbá láti 11 dé 20

4 lines
29.

Darukọ ọrọ-iṣe mejii

4 lines
30.

Onka èdè Yorùbá wò ni yíí?

4 lines