wayground logo

Free Printable Worksheets

Font size

S
M
L
XL
Worksheets

Èdè Yorùbá

Total questions: 5

Worksheet time: 3mins

Name
Class
Date
1.

Orúkọ ọmọ ni (a)  

2.

Èwo ni kìí se ọkàn lára orúkọ tí a ń pè ọmọ titun?

a)

Tufulu

b)

Ìkókó

c)

Arúgbó

3.

Gbolohun ....... maa n ni ọ̀rọ̀ -iṣe kan soso. Gbólóhùn.......

a)

Abọ́de

b)

Ọlọ́pọ̀ Ọ̀rọ̀ Ìṣe

c)

Alákànpọ̀

d)

Onibọ̀

4.

A maa n lo ọ̀rọ̀ arọ́po orúkọ láti fi _____ ọ̀rọ̀ orúkọ nínú gbólóhùn èdè Yorùbá

a)

A. jeba

b)

Dípò

c)

Kàwé

d)

Sọ̀rọ̀

5.

Ayẹyẹ ọjọ́ ìbí mi ti o kọjá' je àpẹrẹ re Àròkọ Oníròyìn

a)

Bẹẹni

b)

Bẹẹ kọ