Font size
WorksheetsYoruba
Total questions: 15
Worksheet time: 8mins
The letter "M" is called_____
M(Mi)
N(ni)
The letter "K" in Yourba is called_____.
K(ki)
J(ji)
The letter "I" is called ______ in Yoruba
i( he)
H(in)
What is the letter "H" called in Yoruba?
L(Li)
H(in)
Daruko ounje Yoruba meji ti o mo.
( Mention two Yoruba foods you know.)
Omo odun melo ni o je?
(How old are you?)
Nibo ni o ti wa ni ilu Nigeria?
(Where do you come from in Nigeria?)
Dahun awon ibeere yi ni ekunrere.
(Answer this questions in details)
Kini oruko re?
Kini itumo Oro yi?
(What is the meaning of this word?) Obirin
Dad
Mom
Boy
Girl
Kini itumo Oro yi?
(What is the meaning of this word?)
Book
Pensulu
Aga
Iwe
Omi
Kini itumo gbolohun yi?
( What is the meaning of this sentence?)
Eja naa n we.
The bird is flying
The fish is swimming
The dog is barking
The sheep is bleating
Kini itumo gbolohun yi?
(What is the meaning of this sentence?)
Mo fe jeun
I need a bathe
I want to sleep
I want to eat
I want to dance
Daruko eya ara marun pelu itumo won ni ede Geesi. ( Mention 5 parts of the body and their English meanings.
Daruko eso metta ti o mo ( Mention 3 fruits you know.)
Bawo ni ase n kini ni aaro? ( How do we greet in the morning?)
Bawo ni?
E kurole
E kaale
E kaaro
