Wayground logo

Free Printable Worksheets

Font size

S
M
L
XL
Worksheets

ALIFABEETI EDE YORUBA

Total questions: 9

Worksheet time: 5mins

Name
Class
Date
1.

Ni ọdun wo ni ede Yoruba di kiko sile? (What year did the Yoruba language become written form?)

a)

1842

b)

1900

c)

1921

d)

1885

2.

Ta ni awon alawo funfun koko n pe awon eya Yoruba? (What were the Yoruba people first called by the whites?)

a)

Aku

b)

Eyo

c)

Egba

d)

Oyo

3.

Ta ni awon eniyan ti won se agbatẹru kiko ede Yoruba sile? (Who were the people who spearheaded the written form of the Yoruba language?)

a)

Ajayi Crowther ati CMS

b)

Obafemi Awolowo

c)

Sango

d)

Moremi

4.

Meloo ni awon iro ti o wa ninu alifabeeti Yoruba? (How many sounds are there in the Yoruba alphabet?)

a)

25

b)

30

c)

20

d)

28

5.

Kọ gbogbo faweli airanmupe ti o wa ninu ede Yoruba. (Write out all the free vowels in the Yoruba language.)

a)

A, E, Ẹ, I, O, Ọ, U

b)

A, E, I, O, U, W, Y

c)

A, E, Ẹ, O, Ọ, U, S

d)

A, Ẹ, I, O, Ọ, U, N

6.

Kọ gbogbo konsonanti ti o wa ninu ede Yoruba. (Pick all the Yoruba consonants)

a)

B, D, F, G, GB, H, J, K, L, M, N, P, R, S, Ṣ, T, W, Y

b)

B, C, D, F, G, H, J, K, L, M, N, P, Q, R, S, Ṣ, T, W, Y

c)

B, D, F, G, H, J, K, L, M, N, P, R, S, Ṣ, T, V, W, Y

d)

B, D, F, G, GB, H, J, K, L, M, N, P, R, S, Ṣ, T, W, Y, Z

7.

oluk--

(a)  

8.

Which sound cannot start a word in the Yoruba language?

a)

b

b)

u

c)

w

d)

i

9.

Iro wo ni ko si ninu alifabeeti ede Yoruba? (Which sound is not in the Yoruba alphabet?)

a)

w

b)

y

c)

c

d)

k