WorksheetsYoruba language basic 1 First term
Total questions: 20
Worksheet time: 40mins
Eya ara wo ni a fi n riran ? (The part of the body used for seeing) .
Oju
Eti
Enu
Se afihan eya ara yi. (Identify)
imu
ọwọ
oju
Ki ni eyi ? (Identify)
oju
eti
imu
A maa n lo _________lati maa rin. (The part of the body used for walking.)
ori
ẹsẹ
ibadi
Se afihan eya ara yi. (Identify )
eku
efi
eti
Itunmo "bath" ni ede Yoruba ni _______(translate)
wẹ
fo
jo
Ki ni itunmo akojopo oro yi .
"Cut your nails"
( translate in Yoruba.)
Fo aso
Jo ijo to dara.
Ge ekanna re.
"Wash your clothes" tunmo si_________________________
(Translate)
Fọ asọ rẹ
Je dodo
Ge ekanna re
"Eat good food at the appropriate time" tunmo si _______________ (translate in Yoruba)
Fo aso re.
ile iwe mi.
Jẹun ti o dara lasiko.
Se afihan eya ara yi. (Identify this part of the body.)
Owo
Ejika
Ori
________________ ni leta akoko alifabeeti Yoruba.
A
B
D
Leta 'L' duro fun ______________
Leta ti o gbeyin ninu alifabeeti Yoruba ni ____________________.
A
GB
Y
Gbogbo leta wonyi ni leta alifabeeti Yoruba ayafi _________.
GB
M
V
Leta alifabeeti Yoruba ni apapo je _______________.
Ogbon (30)
Aarundinlogbon (25)
Eejila (12)
Melo ni faweli alifabeeti Yoruba ?
Meje (7)
Eyokan (1)
Mewa (10)
"Good morning " tunmo si _______________
E kabo
E kaaro
E kule
Aworan yi so nipa ______________
Ere
Ijapa
Ikini
"Good afternoon" tunmo si _____________
Dide
Joko
E kaasan
"Bye bye" tunmo si __________
O dabo
Gege
Pensulu
