Font size
WorksheetsYoruba
Total questions: 29
Worksheet time: 19mins
Ami ohun meloo lo wa ninu ede Yoruba?
Meta
Meji
Marun-un
Merin
Boluwatife je oro silebu meloo
Marun-un
mefa
merin
meta
option 1
Gbogbo alifabeeti ede Yoruba je
Ogbon
Meedogbon
Mejidinlogun
Merindinlogon
Igbeyawo je adehun pataki laarin.......... ati........ lati jo ma gbe po bi Oko ati Aya.
Omode ati Okunrin
Obinrin ati Obinrin
Okunrin ati Obinrin
Okunrin ati Agbalagba
Option 3
........ ni eya Yoruba ti won feran “gaari ati eja’’ bii ounje
Ilorin
Ondo
Ijebu
Eko
Option 3
’Safe journey’ tumo si
Odabo
Oko Arifo
Ekabo
Ekasan
Option 2
Ami ohun meloo lo wa ninu ede Yoruba
merin
meta
eyo kan
mefa
Ara awon ohun elo fun idana Igbeyo ni ile Yoruba ni
Oba ati Ada
Kumo ati odo
Isu ati Apoti aso
Omi ati Ose
Option 3
"Eetalelogun" je ____________ ni figo.(Write in figure.)
23
35
25
Ewo ni kii n ise asa iranra-eni-lowo ninu awon iwonyi?
ole jija
Ajo dida
Arokodoko
Owe sise
option 1
Gbogbo alifabeeti ede Yoruba je
Ogbon
Meedogbon
Mejidinlogun
Merindinlogon
Iro faweli ti kii bere oro ni ede Yoruba ni ........
/e/
/a/
/u/
/i/
Pin oro yii si silebu 'Alayinlohun'
A/loy/in/loh/un
A/lo/yin/lo/hun
A/loyin/lo/hun
Al/oy/i/n/loh/u/n
Orisirisi litireso melo lowa ninu ede Yoruba
meji
meta
merin
ere itage
meji
OLORUN: bi igbagbo Yoruba tumo si eni ti o _______.
ni emi gbogbo wa
ni orun
seda ohun gbogbo
tobi julo
Ewo ni kii n ise asa iranra-eni-lowo ninu awon iwonyi?
ole jija
Ajo dida
Arokodoko
Owe sise
option 1
Orisa ile Yoruba ni...
Ogun
Olundun
Elede
Ologbo
Abiku
Okan ninu konsonanti Yoruba ni ___________________________
B
C
X
V
"i" duro fun ________
Fi aworan yii dahun ibeere yii.
Omo...
Jeun
Patewo
Duro
Jokoo
Fáwẹ̀lì àìránmúpé mélòó ni ó wà nínú èdè Yorùbá
Márùn-ún
Méje
Mẹ́fà
Mẹ́jọ
ÒǸKA YORÙBÁ. (ÌBÉÈRÈ 7-10).
‘Ogójì means
20
30
40
50
‘Welcome’ ni
Ẹ káàsán
Ẹ wọ́lé
Ẹ káalẹ́
Ẹ káàbọ̀
AÁYAN ÒGBUFÒ (ÌBÉÈRÈ 16-20)
‘Sunday’ is known as _______ in Yorùbá.
Ọjọ́ àìkú
Ọjọ́ ìṣẹ́gun
Ọjọrú
Ọjọ́ àbámẹ́ta
‘Igi àgbọn’ means ________
Pineapple tree
Pawpaw tree
Cocoa tree
Coconut tree
‘Ó ra aṣọ lánàá’. The verb in the sentence is ____
Ó
rà
aṣọ
lánàá
Ọ̀RỌ̀ ÀTI ÌDÀKEJÌ ( ÌBÉÈRÈ 26-30).
Opposite of ‘Ọ̀rẹ́’
Ijà
ọ̀tá
ẹgbẹ́
àbúrò
ÀṢÀ ÀTI ÌṢE(ÌBÉÈRE 31-50)
Èwo ni kìí ṣe oúnjẹ àwọn Yorùbá nínú wọ̀nyí
àmàlà
ẹ̀bà
iyán
túwó
Ọjọ́ mélòó ló wà nínú ọ̀sẹ̀?
Mẹ́ta
mẹ́rin
márùn-ún
méje
