
ISE SISE YEAR 8 BLUE
Authored by Cecilia Oguntimehin
World Languages
8th Grade
Used 1+ times

AI Actions
Add similar questions
Adjust reading levels
Convert to real-world scenario
Translate activity
More...
Content View
Student View
20 questions
Show all answers
1.
MULTIPLE CHOICE QUESTION
30 sec • 2 pts
___________ ni awon esin ajeji ti won wa ni awujo Yoruba yato si esin abalaye.
Esin esu
Esin ajeji
Esin orunmila
Esin ifa
2.
MULTIPLE CHOICE QUESTION
30 sec • 2 pts
Ewo ni o lodi si esin ode-oni?
kirisiteni
gurumaraji
obatala
Buda
3.
MULTIPLE CHOICE QUESTION
30 sec • 2 pts
OLORUN: bi igbagbo Yoruba tumo si eni ti o _______.
ni emi gbogbo wa
ni orun
seda ohun gbogbo
tobi julo
4.
MULTIPLE CHOICE QUESTION
30 sec • 2 pts
Iwonyii ni awon Yoruba ka orisa si, ayafi;
Alarina
Alagbawa
Olodumare
Onigbowo
5.
MULTIPLE CHOICE QUESTION
30 sec • 2 pts
Esin ibile __________ ni o fi igbagbo Yoruba han ninu igbe aye miiran leyin iku.
Egungun
orunmila
ifa
esu
6.
MULTIPLE CHOICE QUESTION
30 sec • 2 pts
Nibo ni awon omoleyin Jesu ti n se ijosin?
Mosalasi
Ojubo legbara
Soosi
ile-kewu
7.
MULTIPLE CHOICE QUESTION
30 sec • 2 pts
Nibo ni awon omoleyin Mohamodu ti n se ijosin?
Mosalasi
Ojubo legbara
Soosi
ile-kewu
Access all questions and much more by creating a free account
Create resources
Host any resource
Get auto-graded reports

Continue with Google

Continue with Email

Continue with Classlink

Continue with Clever
or continue with

Microsoft
%20(1).png)
Apple
Others
Already have an account?