WorksheetsYoruba
Total questions: 10
Worksheet time: 20mins
Name
Class
Date
1.
Leta ti o gbeyin alifabeeti ede Yoruba ni ___________________
a)
Y
b)
K
c)
F
d)
G
2.
Leta "E " duro fun _____________
a)
b)
c)
d)
3.
Leta wo ni ko si ninu alifabeeti ede Yoruba ?
a)
GB
b)
W
c)
Q
d)
J
4.
________________ni ege oro ti emi le gbe jade ni ekan soso .
a)
Oluko
b)
Apeere
c)
Amin
d)
Silebu
5.
ITUNU je silebu melo?
a)
merin
b)
okan
c)
meji
d)
meta
6.
Awon aworan wonyi so nipa silebu oloro meta ayafi _____
a)
b)
c)
d)
7.
"Lord " tunmo si ________
a)
Oluwa
b)
Alagbara
c)
Itunu
d)
Olowogbogboro
8.
"Olugbala"tunmo si ___________ni Geesi.
a)
Our Healer
b)
The ancient of Days
c)
The Beginning and The End
d)
Our Saviour
9.
"The Silent Judge"tunmo si______________________.
a)
Alade Ogo
b)
Gbanigbani
c)
Adakedajo
d)
Oluwa
10.
Gbogbo leta alifabeeti Yoruba je___________________________.
a)
Eesan
b)
Ookandinlogun
c)
Ogun
d)
Aarundinlogbon
100 %
