wayground logo

Free Printable Worksheets

NEW

Font size

S
M
L
XL
Worksheets

Nigerian Language (YORUBA)

Total questions: 10

Worksheet time: 5mins

Name
Class
Date
1.

Oro to n so isele inu gbolohun ni .........

a)

oro oruko

b)

oro ise

c)

oro eyan

d)

oro aponle

2.

Awon idile to maa n lu ilu ni a n pe ni.................

a)

Onirara

b)

Onilu

c)

Ayan

d)

Alaro

3.

Orirun eya Yoruba ni ............

a)

Ile Ife

b)

Ilu Oyo

c)

Ilu Meka

d)

Ilu Eko

4.

Awon oge sise yii je ti ode oni ayafi ..........

a)

irun dindin

b)

ete kikun

c)

osun kikun

d)

bata gogoro wiwo

5.

Ewo ni oro aponle ninu iwonyi:

Toluwanimi goke kiakia lo gba adura ni oke Orio

a)

goke

b)

adura

c)

kiakia

d)

Toluwanimi

6.

Agbe .......... ni o n da oko si egbe ile re

a)

Agbe olohun ogbin

b)

Eleran osin

c)

Aladaa nla

d)

Alaroje

7.

Ipese ise ipese owo, ipese igi idana.

Iwonyi je iwulo ise ...........

a)

agbe

b)

ilu lilu

c)

agbede

d)

onigbajamo

8.

Gbaguuda naa ni a n pe ni .............

a)

eja

b)

ewa

c)

ege

d)

iresi

9.

Kini idahun si ikini yii 'Eyin mama a dara o'

a)

Amin e seun

b)

A o ni riru e mo

c)

Ese a tele layo

d)

Ayo a kari

10.

Ewi ohun ti a fi i tu ogun loju ko wa pe;

a)

O dara ki ogun woluu

b)

ki a ma dasi eto ilu

c)

ki a se ohun to ye lati dena ogun niluu

d)

Ki a fi agbo tore