wayground logo

Free Printable Worksheets

Font size

S
M
L
XL
Worksheets

2nd Test Yoruba for year four

Total questions: 10

Worksheet time: 5mins

Name
Class
Date
1.

Iro ede ni _____ to a le fi eti gbo ninu ede.

a)

Ariwo

b)

Ege

c)

Ohun

d)

Ipin

2.

Faweli Yoruba ni _________

a)

B

b)

E

c)

T

d)

S

3.

Iwe meji ,ati iwe meta ji iwe ______

a)

Meji

b)

Meta

c)

Merin

d)

Marun_un

4.

Baba, iya ati omo meji je eniyan _____

a)

Kan

b)

Meji

c)

Merin

d)

Marun_un

5.

Konsonanti inu alifabeeti Yoruba je _____

a)

5

b)

18

c)

20

d)

25

6.

______ ni Awon Ami ti a maa lo nigba ti a ba ko nkan sile Lori iwe tabi Lori nkan mirran ni ibamu pelu bi Awon Yoruba se n soro.

a)

Faweli

b)

Pentuseson

c)

Gbolohun

d)

Konsonanti

7.

_____ ni Ami ti o maa n wa ni pari gbolohun ibeere.

a)

Idanuduro die

b)

Idanuduro

c)

Ami beere

8.

"Osu ope" je ______ ni ede Yoruba.

a)

December

b)

November

c)

September

d)

March

9.

Ojo Abamata je ____________

a)

Sunday

b)

Monday

c)

Friday

d)

Saturday

10.

Faweli airanmupe je _____

a)

Marun_un

b)

Meji

c)

Meta

d)

Meje