wayground logo

Free Printable Worksheets

Font size

S
M
L
XL
Worksheets

Yoruba Government Vocabulary

Total questions: 10

Worksheet time: 10mins

Name
Class
Date
1.

Kini itumo 'reception' ni ede Yoruba?

a)

Iyàrá Ìpàdé

b)

Ibi igbalejo

c)

Ilé oúnjẹ

d)

Igbonse

2.

Ewo ninu awọn aṣayan yi lo tumọ si "Director"?

a)

Olùdarí

b)

Gómìnà

c)

Minisita

d)

Akowe

3.

Kini itumo 'Department' ni ede Yoruba?

a)

Ẹ̀ka

b)

Iranse

c)

Ìgbìmọ̀

d)

Ofisi

4.

Bawo ni a ṣe le so 'President' ni ede Yoruba?

a)

Aṣojú

b)

Sènétọ

c)

Aare

d)

Osise

5.

Translate to English "Kí ni àwọn iṣẹ́ tí Ẹ̀ka Ètò Ìṣúná ń ṣe?"

a)

What is the department of budget meant for?

b)

what are the functions of the department of finance?

c)

What kind of work is typically done in the budget department?

d)

What does the department of finance do?

6.

Translate to English "Ẹ̀ka ìjọba wo ló wa fún irin ajo?"

a)

Which part of the government is for travel matters?

b)

What department of the government is meant for travel?

c)

Which department of government travels?

d)

What branch of the government is responsible for travelling?

7.

Translate to English "Báwo ni Ẹ̀ka Ìjọba Ọ̀gbìn ṣe ń ṣe ìrànlọ́wọ́ fún àwọn àgbẹ̀?"

a)

Will the Department of Agriculture help farmers?

b)

Do farmers get help from the Department of Agriculture

c)

How does the Department of Agriculture help farmers?

d)

What do the department of Agriculture do for farmers?

8.

Mo ń ṣiṣẹ́ ní ẹ̀ka

4 lines
9.

 Ẹmi ni...

4 lines
10.

Bawo ni a ṣe n sọ 'budget' ni ede Yoruba?

a)

owo

b)

Ìṣúná

c)

owo ijoba

d)

inawo