WorksheetsYEAR 11 YORUBA SECOND TERM EXAM
Total questions: 20
Worksheet time: 10mins
Leta ti a ko si Giwa ile eko wa ni _______
leta gbefe
leta aigbefe
leta ikini
Ni ikadii leta aigbefe,oruko akoleta maa n wa ni ______
soki
kikun
apa otun ati osi akoleta
Ipo akowe--yewe---owo---wo je apeere aroko _____
aroko alalaye
aroko asapejuwe
leta Kiko
Itumo oyigiyigi ni ______
eni ti o da aye
eniti agbara re ka gbogbo aye
eni ti o tobi ti a Kori ohun fi we
Oruko miiran ti awon Yoruba n pe Oloun ni________
Eleda
Orisa
Obatala
Itumo paddle your canoe ni_____
so ara re
gbo ti e
je oludari oko oju omi
Pese bi Ogun iya,aninilara bi Ogun baba.Owe yii maa n jeyo nibi pinpin ogun _________
baba
molebi
iya
Ninu Iparoje,oniewedu yoo di ________
oniwedu
elewedu
eleweedu
Pipa iro kan je ninu eyo oro kan tabi laarin oro ni a n pe ni _______
isunki
aranmo
Iparoje
Awon wonyi ni akopa ninu eto idajo ose oni ayafi_______
agbejoro
ile ise gbohun safefe
igbimo eleti gbaroye
Awon won yi ni eto idajo laye atijo ayafi ________
idajo lodo baale
idajo lodo oba ilu
ile ejo giga
Oro ti enikan so ti a few so fun elomiiran gege bi o ti so ni ______
oro ayalo
oro agabaso
aayan ogbufo
Bibeli je apeere oro ayalo _______
afetiya
afojuya
akosile
Oro ti a ko sile gege bi awon elede se n pe ni _______
akosile
afetiya
afojuya
Ninu eto ogi pinpin,_______ ni o maa n Koko mu.
beere
aremo
daodu
Gbogbo awon yi leto si Ogun pimpin ayaafi ________
iyawo oku
omolooku
egbon oku
Ohun ini ti eni toku fi sile ni ______
gbese
Ogun
oko owo
Akobi lobinriin ni won n pe ni________
aremo
daodu
beere
Ohun to duro bii leta Kiko lode oni laye atijo ni ____
aroko pipa
aroko Kiko
leta Kiko
Bi a ba gbe itufu si eyinkule enikan o tumo si pe _______
ki eniyan naa jawo kuro nibi agbere sise
ki eniyan maa mura Ogun sile
eniyan naa sewa a si fe dana sun ile re
