WorksheetsABDUSSALAM
Total questions: 30
Worksheet time: 45mins
Ona miiran wò ni a lẹ gba sọ "Mo"
Awọn
Eyin
Emi
Iwo
Ki ni a n pe "Grandma" ni ede yoruba
Iya Agba
Iya
Mamẹ
Ẹgbọn
Kini 22 n ede yoruba
Eeji le lokanla
Eeji le logun
Eejọ din lọgbọn
So ọrọ yí ni ede gẹẹsi "Mo fẹ sún si orí ibusun"
He wants to sleep on the chair
They want to dance on the table
We want to sleep on the bed
I want to sleep on the bed
Ti a ba fi eejo kun eeta, kini ọ ma fún wa?
Aarun
Ookanla
Eésan
Eeji
Bawo ni a ṣe sọ "Wẹ" ni ede yoruba?
A
Irẹ
Mo
O
Kini a n pe eni to bi wa ni ede yoruba?
Aburo
Agba
Iya
Sọ òrò yíì ni ede yoruba " They want to wash cloth"
Mo fẹ wọ aṣọ
Òun fẹ jẹ aṣọ
Won fẹ fọ asọ
Ona miiran wò ni a lẹ gbà sọ O (you)
Iwo
Àwọn
Eyin
A
Kini ọ ma n fi n joko?
Apoti
Ibusun
Tabili
Aga
Bawo ni a ṣe ma n ki ará wa ni ọsan
Eku irole
Ẹkaasan
Ẹẹkaarọ
Ki ni o ma pè Abdurrahman ni ede yoruba?
Ẹgbọn
Aburo
Ọmọ ìyà mi
Kini awon won yi jẹ ṣi e? "Baba, Iya, Àbúrò, Ẹgbọn
Ẹbi
Akẹẹkọ
Olùkọ
Orẹ
Kini eeji dín logun ni ede gẹẹsi
12
28
18
Ìtumò Egbon ni kini?
Younger sister/ brother
Elder brother/ sister
Twin brother or sister
Lo ọrọ arọpo yinpelu omiran re "Mo jẹ iresi mí"
Àwọn jẹ irẹsi
O jẹ iresi
Èmi jẹ iresi
"A fẹ ra ponginla" Kini ra nínú òrò yíì?
Oro arọpo orukọ
Ọrọ ise
Ọrọ orukọ
Ọrọ atokun orukọ
Mo fẹ ----- aso ile iwe mi
Je
Fọ
Wa
Lo
Fi owo kan oju re
Tá ni olori ẹbi?
Baba
Iya Agba
Baba Agba
Ka onka èdè yoruba lati 21-25
Sọ ọnà oriṣii ti a lẹ gba kì eniyan
Darukọ oun inú ilé meerin ti o mọ
Darukọ ebí inu ilé máàrún tí o mọ
Sọ òrò wonyi ni ede yoruba
They want to dance
We want to buy candy
Mummy washed Cloth
Darukọ ọrọ ìse ti o wan nínú òrò yíì
Mummy se iṣu
Abdussalam fò asọ re
Ọmọ ọdún melo ni e?
