Font size
WorksheetsHAMEEDAH
Total questions: 30
Worksheet time: 40mins
Da ọrọ ìse tó wà nínú òrò yíì mó
" mummy ra ponginla fún wa"
Fun
Wa
Ra
Ponginla
Eya Ara wò ni o ma n fi jeun?
Igunpa
Enu
Ẹsẹ
Ẹbí rè wọ lọ mo
Iya
Baba
Aburo
Iya Agba
Bawo ni a ṣe ki ará wa ni Alẹ
Eku irole
Ẹkáàbọ̀
Ẹẹkaarọ
Ẹẹkalẹ
Bawo ni o ṣe ma pé àwon baby brother re ni ede yoruba?
Ẹgbọn
Aburo
Aburo baba
Ti a ba ro eefa pọ mọ ookanla, kini ọ ma fún wa?
Aarun
Ẹẹta dinlogun
Eeji le logbon
Eeta din lọgbọn
Kini itumo "Mi"
Mine
Their
Your
My
Eya ara Re wo ni o ma n fi ri?
Ọwọ
Ẹsẹ
Itan
Ona miiran wò ni a lẹ gba sọ "WE"
Awa
Àwọn
Oun
Sọ ọrọ yi ni ede gẹẹsi
"Ọwọ mi àti ẹsẹ mi"
My leg and my hand
Their hands and their legs
My hand and my leg
Kini itumo rẹ
Your
Their
It's
His / her
Tani olórí ẹbi inu ile?
Baba Àgbà
Baba
Baba ibeji
Iya
Awon fẹ jẹ iṣu pelu dodo " Kini ọrọ arọpo inu ọrọ yìí?
Dodo
Pelu
Je
Àwọn
Kini itumo ìwé re
His/ her book
Your book
Their book
"se" túmọ sí?
To cook
Do/ can
To keep
Ti a ba ló ṣe ninu ọrọ, kini a má n fi daun?
A ma fi ori
Mi o mọ
Yes/no
Bẹẹni tabi bẹẹkọ
Sọ ọrọ yi pẹlú ọrọ arọpo orukọ mìíràn
" A fẹ kó Si ile iwe"
Eyin
Oun
Awa
Re
Won fẹ ---- iṣu
Se
Fo
Rin
Lọ
Àwọn ---- ori ibusun ilẹ wọn
Rin
Sun
Jo
Fo
Kini túmọ sí?
What
Are
Is
Darukọ awọn ebi mẹrin ti o mọ
Darukọ eya ara meerin ti o mọ
Ka onka èdè yorùbá láti 10-20
So awọn ọrọ yí
" My name is Hameedah, I am 8 years, I love strawberry, I love my father, sister, and my brother. I want to become a doctor.
Darukọ ọrọ ìse máàrún
Darukọ ọrọ arọpo orukọ meerin
So awọn ọrọ arọpo orukọ ti o darukọ sí omiran
Túmọ ọrọ yí
" Won fẹ iṣu ati dodo"
Darukọ òún elo inu ile meerin
Darukọ ẹranko meerin
