WorksheetsYORUBA YEAR 8 EXAM
Total questions: 54
Worksheet time: 27mins
____ jẹ́ àpẹẹrẹ oge ṣíṣe ayé àtijọ́.
eyín pípa
táì lílò
ètè lílu
bẹ́líìtì lílò
Oge ṣíṣe ayé òde-òní nìyí àfi ______.
eyín pípa
táì lílò
ètè lílu
bẹ́líìtì lílò
Àpẹẹrẹ gbólóhùn àṣẹ ni
wá.
omọ dà?
Mo ra ìwé
Ọmọ́bọ́lánlé ti lọ.
Àpẹẹrẹ gbólóhùn ìbéèrè ni ______.
Ta nì ìyẹn?
lọ
Mo ra ìwé
Ọmọ́bọ́lánlé ti lọ.
‘Ọmọ àti ìyá kú’Jẹ́ àpẹẹrẹ gbólóhùn
abọ́dé.
alákànpọ̀.
àṣẹ
oníbọ.
Ìgbéyàwó ilẹ̀ Yorùbá pín sí ìsọ̀rí _____.
mẹ́ta
méjì
mẹ́rin
márùn-ún
Lára ohun èlò ìdána nínú ìgbéyàwó ìbílẹ́ ni
kùránì.
ataare.
àtíbàbà
òrùka.
Irúfẹ́ ìgbéyàwó tó wọ́pọ̀ láàrìn àwọn alákọ̀wé lóde-òní ni ìgbéyàwó
ṣóòsì.
kóòtù.
alárinà.
ìsoyìgì.
Òjìlélọ́ọ̀ọ́dúnrún ó lé mẹ́wàá ni _____.
330
360
370
350
‘480’ni______.
ọ̀rìnlélọ́ọ̀ọ́dúnrún
ọ̀tàlénírinwó
òjìlénírinwó
ọ̀rìnlénírinwó
Ohun èlò ìsọmọlórúkọ ayé àtijọ́ ni _____
ìgbín.
kùránì
ata
oyin
Ìgbésẹ̀ kì-ín-ní nínú àròkọ ni_______.
ìfáàrà
ìkádìí
ìlapa èrò
kíkọ orí-ọ̀rọ̀
Àwọn ohun tó n fa ogun nìyí àfi ___.
ààlà ilẹ̀
sùnmọ̀mí gbígbé.
oyè jíjẹ
ọ̀rọ̀ ẹ̀yìn.
Ohun ìjà ogun ni ___.
ajá
òkò
aṣọ
kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́
Ìdáhùn fún ‘Ẹ kúùrọ̀lẹ́ ’ni ẹ _____.
káàbò
káalẹ́
kúùrọ̀lẹ́
ìrọ̀lẹ́
Àwọn tí à n kí ní “Ẹ kú ọwọ́ lómi” ni ____.
eni tó n dáná lọ́wọ́
eni tó n mu gaàrí lọ́wọ́
eni tó ṣẹ̀ṣẹ̀ bímọ
eni tó n fọṣọ lọ́wọ́
Èwo ni kì í ṣe ìwà ọmọlúwàbí?
Òótọ́ sísọ.
ìbọ̀wọ̀fágbà.
Ọ̀bùn síṣe.
ìkíni.
Àròkọ tí a fi n sọ nipa ìṣẹ̀lẹ̀ tó ṣojú ẹni tàbí èyí tí a gbọ́ ni àròkọ
onílẹ́tà
alápèjúwe
oníròyì
kì í ṣe ìwà ọmọlúwàbí?
Òótọ́ sísọ.
ìbọ̀wọ̀fágbà.
Ọ̀bùn síṣe.
ìkíni.
Àròkọ tí a fi n sọ nipa ìṣẹ̀lẹ̀ tó ṣojú ẹni tàbí èyí tí a gbọ́ ni àròkọ
onílẹ́tà
alápèjúwe
oníròyìn
alálàyé
Òrìṣà ilẹ̀ Yorùbá ni ______.
Ìfà
Ìfá
Ifà
Ifá
Létà gbẹ̀fẹ̀ ni létà tí à n kọ sí
ọ̀gá ilé-ìwé
olóòtú ìwé ìròyìn
olùkọ́
Àbúrò bàbá ẹni
_____ kì í ṣe àbùdá létà gbẹ̀fẹ̀.
Déètì kíkọ
Àdírésì akọlẹ̣́tà
ara lẹ̣́tà
Àkọlé kíkọ
Orúkọ yìí kò sí nínú orúkọ tí Yorùbá n pe Olódùmarè
Aṣẹ̀dá
Atẹ́rẹrẹkáyé.
Ọlọ́run
Aládàá-nlá
Àwọn Yorùbá gbàgbọ́ pé Olúdùmarè kìí____
sòrọ̀
kú
rìn
ṣáré
Àwọn Yorùbá gbàgbọ́ pé ___ jẹ́ alárinà láàrin èdá àti Ẹlédàá.
Olódùmarè
Òrìṣà
Ànábì
Àlùjànnú
Àpólà-ìṣe lè ní ìwònyí àfi
ọ̀rọ̀-ìṣe
olùwà
àbọ̀
ẹ̀yán
Àwọn ewì alohùn tí à n fi ọ̀rọ̀ inú wọn dá mọ̀ pín sí ọ̀nà
méjì
mẹ́ta
márùn-ún
mẹ́rin
_____ jẹ ọba ní ìlú Ọ̀yó.
Ṣàngó
Ọya
Ifá
Ògún
'A kìí ṣá ginni lógbé' jẹ́ àpẹẹrẹ ________.
ọfọ̀
ẹsẹ ifá
ewì
oríkì orílẹ̀
“Ìyèrú òkín ọmọ Ọlófàmọjò' jẹ mọ́ _______.
Oríkì orílẹ̀
ẹsẹ ifá
ọfọ̀
ewì
‘Rírú ẹbọ ní gbeni’ jẹ mọ́ _______.
ẹsẹ ifá
Oríkì orílẹ̀
ọfọ̀
ewì
Lẹ́tà kíkọ pín sí ọ̀nà ___ nínú èdè Yorùbá.
méjì
mẹ́ta
kan
márùn-ún
Lẹ́tà _____ni lẹ́tà tí à n kọ sí ẹni mímọ̀.
àìgbẹ̀fẹ̀
gbẹ̀fẹ̀
àìgbagbẹ̀fẹ̀
gbẹ̀fẹ̀ àti àìgbẹ̀fẹ̀
Lẹ́tà ìwáṣẹ́ ni lẹ́tà________.
gbẹ̀fẹ̀
àìgbẹ̀fẹ̀
onígbẹ̀fẹ̀
gbẹ̀fẹ̀ àti àìgbẹ̀fẹ̀
Ọ̀rọ̀ tí ó jẹ́ kókó inú gbólóhùn ni
ọ̀rọ̀-orúkọ
ọ̀rọ̀-ìṣe
ọ̀rọ̀ arọ́pò-afarajorúkọ
ọ̀rọ̀
wáṣẹ́ ni lẹ́tà________.
gbẹ̀fẹ̀
àìgbẹ̀fẹ̀
onígbẹ̀fẹ̀
gbẹ̀fẹ̀ àti àìgbẹ̀fẹ̀
Ọ̀rọ̀ tí ó jẹ́ kókó inú gbólóhùn ni
ọ̀rọ̀-orúkọ
ọ̀rọ̀-ìṣe
ọ̀rọ̀ arọ́pò-afarajorúkọ
ọ̀rọ̀-àpọ́nlé
Ajá dúdú ní ojú _____.
mẹ́rin
méjì
márùn-ún
mẹ́ta
Kí ni àpólà?
Ìyà
Èdè òfin
Èyọ ọ̀rọ̀ kan tó jẹ apá gbólóhùn
Orúkọ ẹni
Àpólà-orúkọ ni?
Ọ̀rọ̀ tó jẹ́ ohun-èlò
Ọ̀rọ̀ tí kò ní ìtumọ̀ kíkún
Ọ̀rọ̀ tí ń ṣe iṣẹ olúwa nínú gbólóhùn
Gbólóhùn títà
Àmi ohùn mẹ́ta ni:
Dúdú, pupa, funfun
Oke, àárín, ìsàlẹ̀
Tóbi, kékeré, alabọ
Àkúnya, ajọṣepọ, alákọmọ
Kí ni ìwà ọmọlúwàbí?
Ìmọ̀ràn
Ìwà tó dára
Ìjìnlẹ̀ èdè
Ìṣepọ ọ̀rẹ́
Òrìṣà ilẹ̀ Yorùbá jẹ́:
300
150
401
1000
"Mo ti yàgbẹ́ tán." Jẹ́ àpẹẹrẹ gbólóhùn ______.
alálàyé
kání
àyísódì
_______ lè mú kí oyún máà bàjẹ́ lára obìnrin.
Àtọ̀sí
Oyún ìju
Inú gbígbóná
Ìdáhùn fún ẹ kú ooru ni ______.
òo
ooru ni o
ẹ̀yin náà n kọ́
Ọjọ́ _____ ni wọ́n n sọ ọmọkùnrin lórúkọ láyé àtijọ.
keje
kẹjọ
kẹsàn-án
Ó dára láti ka àyọkà tó ìgbà ____ sí _____.
méjì sí mẹ́ta
méjì sí mẹ́rin
méjì sí márùn-ún
A lè rí pápá ìṣeré ní ilé-ẹ̀kọ́.
bẹ́ẹ̀ ni
kò dára
rárá
A lè ṣe àtúnpín lítíréṣọ̀ alohùn sí ọ̀nà _____.
méjì
mẹ́ta
márùn-ún
'Iṣu mélòó ni o rà?' Jẹ́ àpẹẹrẹ gbólóhùn _______.
àṣẹ
kání
ìbéèrè
/ɛ/ ni _______.
e
ẹ
ọ
/j/ ni _____.
y
j
jí
