WorksheetsYORUBA SS1
Total questions: 20
Worksheet time: 10mins
Name
Class
Date
1.
Ade din isu je ni ana,Oro ise meloo lowa ninu Gbolohun yii?
a)
merin
b)
meta
c)
meji
d)
eto kan
2.
Sola wa sugbon ko ri wa, Ewo ni Oro asopo ninu Gbolohun yii?
a)
sugbon
b)
ko
c)
ri
d)
mi
3.
Yoruba gbagbo pe Gbogbo wa ni a je gbese
a)
ise
b)
iku
c)
owo
d)
omo
4.
Ikan Lara Awon wonyi je iranse Pataki fun eledumare
a)
ogun
b)
ifa
c)
iku
d)
sango
5.
Kinni anpe Eni ti o maa nduro larin oko ati aya
a)
alarina
b)
obinrin
c)
ale
d)
aburo oko
6.
Asa Oge sise wopo julo Nile Yoruba laarin Awon
a)
omidan
b)
agbalagba
c)
okunrin
d)
Awon Omode
7.
Aderemi Ra Bata meji ,Ewo ni Oro ise
a)
aderemi
b)
Ra
c)
Bata
d)
meji
8.
Ewo ni kiise iwa omoluabi ?
a)
ifowo ola gbani loju
b)
ibowo fun agba
c)
itelorun
d)
iteriba
9.
Idi ti afi ma ntoju Ara wa ni lati dena
a)
iku
b)
wahala
c)
Arun
d)
inawo
10.
Iwa ti o to ki obi fi ko Omo lati kekere ni
a)
Eko iwe
b)
Eko ile
c)
Oro siso
d)
ijajiji
11.
Eetadinlogota tumo si
a)
53
b)
63
c)
57
d)
67
12.
Kinni aadota ni ede geesi?
a)
50
b)
60
c)
69
d)
70
13.
Nibo ni orisun Ile ede yoruba?
a)
ede
b)
ife
c)
akure
d)
Oyo
14.
Eyi ni ko si Lara oun elo isomoloruko
a)
oyin
b)
omi
c)
iyo
d)
adin
15.
Silebu meloo lowa ninu Gbolohun yii (afasegbojo)
a)
marun
b)
mesan
c)
mejo
d)
meedogun
16.
Faweli meloo lowa ninu Gbolohun yii, alagbara
a)
eeyokan
b)
mewaa
c)
merin
d)
mefa
17.
Akoto ede yoruba ode oni ni
a)
oshogbo
b)
osogbo
c)
osoogbo
d)
osogboo
18.
ni oma nsunkun iyawo
a)
Awon ore iyawo
b)
idile oko
c)
iyawo
d)
oko
19.
Ta ni baba nla Yoruba?
a)
oduduwa
b)
oranmiyan
c)
Okanbi
d)
olowu
20.
Ewo ni kii se orisi igbeyawo
a)
igbeyawo soosi
b)
igbeyawo kootu
c)
igbeyawo masalasi
d)
igbeyawo Ile iwosan
100 %
