Iṣẹ Ile Ti Mo Feran Ati Ti Mi O Feran

Iṣẹ Ile Ti Mo Feran Ati Ti Mi O Feran

1st Grade

6 Qs

quiz-placeholder

Similar activities

Dagiti kabaelak ti tunggal tawen QUIZ 2

Dagiti kabaelak ti tunggal tawen QUIZ 2

1st Grade

10 Qs

suku kata

suku kata

KG - University

10 Qs

PALABRAS con "K"

PALABRAS con "K"

KG - 1st Grade

10 Qs

kemahiran kvkv

kemahiran kvkv

1st Grade

10 Qs

Bahasa Melayu

Bahasa Melayu

1st - 3rd Grade

10 Qs

LETRA T/t

LETRA T/t

1st Grade

10 Qs

Formulación de Palabras

Formulación de Palabras

1st - 7th Grade

7 Qs

Kemahiran 14 - Perkataan  KV KV KVK

Kemahiran 14 - Perkataan KV KV KVK

1st - 6th Grade

10 Qs

Iṣẹ Ile Ti Mo Feran Ati Ti Mi O Feran

Iṣẹ Ile Ti Mo Feran Ati Ti Mi O Feran

Assessment

Quiz

Other

1st Grade

Hard

Created by

Quizizz Content

FREE Resource

6 questions

Show all answers

1.

MULTIPLE CHOICE QUESTION

30 sec • 1 pt

Tẹ́ bẹ́ẹ̀dì

Mo fẹ́ràn láti tẹ́ bẹ́ẹ̀dì

Mo fẹ́ràn láti jẹun

Mo fẹ́ràn láti sun

Mo fẹ́ràn láti ká

2.

MULTIPLE CHOICE QUESTION

30 sec • 1 pt

Gbálẹ̀

Mo fẹ́ràn láti gbálẹ̀

Mo fẹ́ràn láti sùn

Mo fẹ́ràn láti jẹun

Mo fẹ́ràn láti rìn

3.

MULTIPLE CHOICE QUESTION

30 sec • 1 pt

Fọ abọ́

Mi ò fẹ́ràn láti fọ abọ́

Mo fẹ́ràn lati ra abọ́

Mi ò fẹ́ràn lati jẹ abọ́

Mo fẹ́ràn lati fọ abọ́

4.

MULTIPLE CHOICE QUESTION

30 sec • 1 pt

Fọ bàtà

Mi ò fẹ́ràn láti fọ bàtà

Mo fẹ́ràn láti ra bàtà

Fọ bàtà ni mo ń ṣe

Mo fẹ́ràn láti fọ́ ẹsẹ̀ mi

5.

MULTIPLE CHOICE QUESTION

30 sec • 1 pt

Fọṣọ

Mo fẹ́ràn láti fọṣọ

Mo fẹ́ràn láti jẹun

Mo fẹ́ràn láti sùn

Mo fẹ́ràn láti ka iwe

6.

MULTIPLE CHOICE QUESTION

30 sec • 1 pt

Nu ilẹ̀

Mi ò fẹ́ràn láti nu ilẹ̀

Mi ò fẹ́ràn lati ra ilẹ̀

Mi ò fẹ́ràn lati fi ilẹ̀ silẹ

Mi ò fẹ́ràn lati nu omi