WorksheetsYoruba exam yr7
Total questions: 54
Worksheet time: 37mins
Okan pataki Lara eto igbeyawo ni ____
Oluko
Alarina
Agbenuso
Alabojuto
Igbese to saaju ninu eto igbeyawo ni
Idana
Ijohen
Ifojusode
Itoro
Onka "okoolelegberun" ni Yoruba ni
120
1200
1020
1050
Oruko miiran fun "okoo" ni
Igba
Egberun
Eewaa
Ogun
Aja ode pa eku kekere kan.
Oro ise oni gbólóohùn yìí ni
Pa
Eku
Ode
Kan
Eni to je baba nla gbogbo awon omo Yoruba ni
Lamurudu
Oduduwa
Ooni
Oranmiyan
Ibi ti Oduduwa tedo si leyin to kuro ni Meka ni
Ile-Ife
Eko
Ibadan
Osogbo
Omo meloo ni Oduduwa?
Meji
Meta
Marun un
Meje
_____ ni orirun gbogbo omo Yoruba
Eko
Abuja
Ibadan
Ile-Ife
____ ni akobi gbogbo awon omo Oduduwa
Orangun
Oranmiyan
Olowu
Alaketu
Igbese akoko ninu eto igbeyawo ni
Ifojusode
Ijohen
Iwadii
Idana
Orisi litireso____ ni o wa
Meji
Meta
Merin
Eyo kan
Litireso Alohun Yoruba pin si ona ___
Meji
Meta
Merin
Marun un
Ekun iyawo je apeere_____
Ere onise
Itan aroso
Ewi atenudenu
Ewi adayeba
Alo apagbe je apeere ____
Itan aroso
Ewi atenudenu
Ere Onise
Akewi n ke
Oduduwa ati awon emewa re lo ojo ____ ki won to rin de Ile-Ife
Aadota
Aadorin
Aadorun un
Aadofa
____ ni o jogun ilè gege bi akoni
Orangun
Oranmiyan
Olowu
Onisabe
Bawo ni a se maa n ki àgbè?
Arokobodunde
Arinpa ogun
Aredu
Igba a ro
____ ni a maa n ki pe 'igba a ro'
Ode
Agbe
Akope
Onidiri
Eni to sese bimo ni a n ki pe
E ku ibimo
E kare
E ku owo lomi
E ku aseyori
Faweli airanmupe Yoruba je ____
Marun un
Meje
Mewaa
Mejila
Faweli aranmupe yoruba je _____
Meji
Meta
Merin
Marun un
Alifabeeti meloo ni o wa ninu ede Yoruba?
Mewaa
Meeedogun
Ogun
Meeedogbon
Ami ohun meloo ni o wa ninu ede Yoruba?
Meji
Meta
Merin
Marun un
Apeere afipe asunsi ni___
Eyin oke
Eyin isale
Imu
Ori
Afipe akanmole ni_____
Aja oke
Ahon
Eye isale
Olele
Edo-foro ni _________
Lungs
Mouth
Airstream
Lip
Eya ara ti a lee foju ri ni ____
Edo-foro
Tan an na
Komookun
Eye isale
Pataki ise agbe ni ipese _______
Ohun jije
Ohun mimu
Ohun nina
Ohun lilo
Asiko ti a maa n sise agbe ni _____
Asiko eerun
Asiko ojo
Asiko Oye
Asiko ooru
Ewo ni ko ba akoto ode-oni mu?
Aye
Aiya
Eye
Ilesa
Ewo ni ko tona pelu akoto?
Osogbo
Ofa
Ogbomosho
Yoo
Ewo ni o tona?
ge gebi
gegebi
gege bi
ge ge bi
Leta gbefe kii ni_____
Adiresi
Deeti
Ikini
Akole
Leta aigbagbefe maa n ni _____ meji
Akole
Oruko
Adiresi
Ikini
Ibuwoluwe maa n waye ninu leta _____
Gbefe
Aigbagbefe
Iwase
Ibanikedun
Apetunpe waye ninu ____
Panapana
Jije
Mimu
Ijekuje
Apetunpe elebe ni ___
Jije
Pada
Duro
Sun
Oruko miiran fun "okoo" ni
Aarun un
Eewaa
Ogun
Ogbon
"Eede" tumo si ____
-10
-20
-50
-100
"Aado" tumo so ___
-100
-50
-10
-20
"Ota" ninu onka je _____
60
3
30
10
"Oji" je ____
2
40
20
200
"Egbe" ninu onka Yoruba je _____
20
50
200
100
Kin ni onka Yoruba fun 1200?
Eejila
Egbefa
Igba
Aadota
"Ojilelegberun ati meji" je
1002
1022
1042
402
Ipinle meloo ni o wa lorile -ede Naijiria?
Merindinlogun
Merindinlogbon
Merindinlogoji
Merinlelogoji
Pari awon owe wonyii....
Ile laa wo ki a to_____
Somo loruko
Ko o
Yale gbe
Wo inu re
Adiye funfun ko _____
More re lagba
See je
Ju dudu lo
See ta
Bami na omo mi ko ____
See so
Denu olomo
Dara to
See na
Taa ni baba nla gbogbo awon Iran Yoruba? (5mks)
Ilu wo ni baba nla awon Iran Yoruba tedo si leyin ti o kuro ni ilu Meka? (5mks)
Daruko awon eya Yoruba marun un ti o mo. (10mks)
Daruko merin lara awon igbese to romo asa/eto igbeyawo ni Ile yoruba
