wayground logo

Free Printable Worksheets

Font size

S
M
L
XL
Worksheets

YEAR 5 YORUBA First CA

Total questions: 10

Worksheet time: 13mins

Name
Class
Date
1.

____________ je Oruko Amutorunwa.

a)

Olaoluwakanmi

b)

Oluwaseyi

c)

Taiwo

2.

________ ni omo ti abi pelu ika mefa. (Six fingers)

a)

Idowu

b)

Olugbodi

c)

Ojo

3.

Ya aworan ti o n soro nipa ifara-eni-sipo-omolekeji.

4.

______ ni love ni ede Yoruba.

a)

Ife

b)

Ibanikedun

c)

Ilawosi

5.

Ko apeere gbolohun keekeeke ti o mo.

4 lines
6.

_____ je oruko amutorunwa.

a)

Adetayo

b)

Oluwaseye

c)

Ajayi

7.

Ka gbolohun keekeeke yi ki o dahun ibeere ti o tele.

Peju wo buba

Kemi we gele

Bisi wo kaba

Wunmi de fila

Gbogbo won woso.

Ibeeree: Kini Wunmi se?

a)

Wunmi ya fila

b)

Wunmi de gele

c)

Wunmi de fila

8.

Daruko oruko amutorunwa marun (5) ti o mo.

4 lines
9.

Kini oruko omo meji ti a bi papo ni ile Yoruba?

a)

Taiwo and Kehinde

b)

Idowu ati Alaba

c)

Ige ati Dada

10.

________ ni ki eniyan maa se si eniyan lona ti o fe ki won maa se si owun.

a)

Eebu

b)

Ifara-eni-sipo-omolakeji

c)

Ija