WorksheetsHameedah
Total questions: 30
Worksheet time: 35mins
Oun elo inu ile wò niyi?
Ikolẹ
Paka
Idọti
Igbalẹ
Ọwọ mélòó ní owa ninu Aworan yii?
Ẹẹrin
Mẹrin
Mẹfa
Eeje
Kini oun èlò inule yì?
Kabinẹẹti
Ifoyin
Aga
Tabili
Bawo ni a ṣe n "l"
Mo
Oun
Iwo
Awọn
Ọnà mìíràn wò ni a le gba sọ Won
Ẹyin
Awọn
Oun
Emi
Kini "Rice" ni ede yoruba ?
Iṣu
Eba
Irẹsi
Gbaguda
Alifabeeti wò ni ati le ba akawe yi pade?
N
Ẹ
E
R
Ewo ni kí n ṣe ọrọ-arọpo orúkọ?
Oun
O
Awa
Wa
Oun elo inule wọ rè?
Abọ
Ikoko
Sibi
Pootii
Oun elo inule wọ ni a má n Fi jeun?
Abo ati Ṣibi
Abọ ati ibusun
Ero amu nkan tutu
Kini 7 ni ede yoruba
Ẹẹjọ
Ẹẹsan
Eeje
Ẹẹwa
Ọnà mìíràn wò ni a le gba sọ "MO" ni ede yoruba?
Awọn
Emi
Ẹyin
Oun
Kini nkan ti a n fin rorin?
Ata gunugun
Ifọyin
Sibi
Aga
Gbogbo nkan won yí ni òun elo inule ayafi?
Ikoko
Abo
Iyẹpẹ
Kabinẹẹti
Eeje ati ẹẹrin a fún wa ni?
Ààrùn din logun
Ọkanla
ẸẸRIN
ẸẸRIN din logun
Iya---isu
Mu
Se
Fo
A má n mu omi?
Raara
Beeni
Kini aworan yii?
Okun
Bẹliti
Bọọlu
Fila
Ewo lo dara fún ọrọ arọpo yíì?
O NI OWO
Iwọ ni owo
Emi ni owo
Mo ni owo
Áwọn ni owo
Kini a má n Fi igbalẹ ṣe?
A n Fi gba idọti
A n Fi duro
A n Fi mú omi
A). Sọ awọn ọrọ wọnyí ni ede yoruba
1). I want to eat rice
Daruko oro iṣe máàrún tí e mo
3). We want to drink water
Daruko awọn oro arọpo orukọ fún eniyan
Darukọ ọrọ-arọpo orúkọ fún eniyan pupo
Daruko oun èlò inule máàrún Ti o mọ?
Daruko akawe meta fun alifabeeti Ẹ
Lọ ọrọ arọpo orukọ yii pelu omiran
8) Wón tá burẹdi
Lọ ọrọ arọpo orukọ yii pelu omiran
9) Ò fẹ rà irẹsi
Lọ ọrọ arọpo orukọ yii pelu omiran
10). Mo jẹ àgbàdo
