WorksheetsGRADE 9 TEST 2
Total questions: 30
Worksheet time: 15mins
BOLA JE EBA. "Bola" ninu gbolohun yii je Oro oruko to n sise ___ ("Bola" in the sentence BOLA JE EBA is used as ___)
Eyan
Oluwa
Abo
Aponle
Isori Oro ___ lo n toka si eniyan, eranko ati ibi. ( ___ is a name of animal, place or thing)
Oro aponle
Oro ise
Oro oruko
Oro atokun
Adiresi meloo ni Leta Gbefe maa n ni? (How many Address does an informal letter have?)
Meji
Okan
Meta
Merin
Leta ___ni o bere alifabeeti ede Yoruba. (___ letter starts the Yoruba alphabet)
F
GB
E
A
Leta ___ ni o gbeyin alifabeeti ede Yoruba. (___ letter ends the Yoruba alphabet)
W
Y
P
R
Igbese akoko ninu Leta Gbefe ni ----. ( The first step in informal letter is ___)
Ipari leta
Akole leta
Adiresi kiko
Deeti kiko
Gbogbo alifabeeti ede Yoruba je ___. (All the letters in Yoruba alphabet are ___)
Merindinlogbon (26)
Meedogbon (25)
Metadinlogbon (27)
Mejilelogun (22)
Faweli ede Yoruba pin si ona ___. (Yoruba vowels are divided into ___)
Meta (3)
Meji (2)
Merin (4)
Marun-un (5)
Apeere fawewli aranmupe ni ___.
A
E
I
UN
Leta ti a ko lati wase ni leta ___. (Letter written for application of job is ___)
Gbefe
Ile-ise
Aigbefe
Oniroyin
Apapo konsonanti Yoruba je ___. (All the Yoruba consonants are ___)
Mejidinlogun (18)
Mejilelogun (21)
Metadinlogun (17)
Merindinlogun (16)
Ewo ni faweeli ninu awon won yii. (Which one is vowel among these options)
E
B
J
F
Ona meji pataki ti a le pin faweli ede Yoruba si ni ___. (The two ways Yoruba vowel can be divided into are ___)
Aranmupe ati Ayanupe
Aranmupe ati Afetepe
Airanmupe ati Aiyanupe
Aranmupe ati Airanmupe
Formal letter tumo si ___
(The Yoruba meaning of formal letter is ___)
Leta Gbefe
Leta Oga
Leta Aigbefe
Leta Kiko
___ ni iru leta ti a maa n ko si awon to sun mo wa
(___is the letter we write to people who are very close to us)
Leta Olowo
Leta Gbeborun
Leta Gbefe
Leta Aigbefe
Leta meji ti o wa ninu ede Yoruba ni___ ati ___
(The two types of letter in Yoruba are___ and ___)
Leta Gbefe ati Aigbefe
Leta Kiini ati Ikeji
Iwe ati Biro
Ebi ati Ore
Leta maa n ni iwonyii ayafi ___
(Letters have these except ___)
Adiresi
Deeti
Ile
Oruko
A gbodo ni idi ti a se ko leta.
(We must have reason for writing letter?)
Bee ko
boya
Ko daju
Bee ni
Deeti se pataki?
(Date is important in letter writing?)
Bee ni
Boya
Bee ko
Ko daju
Gbogbo leta wonyii ni o wa ninu alifabeeti Yoruba ayafi ___. (All these letters are in Yoruba alphabet except ___)
E
GB
P
Z
___ ni ohun ti a fi n se iyato laarin oro meji ti o ni sipeeli kan naa. (___is used to differentiate two words with same spellings)
Ami ohun
Iro ede
Oro
Ede
Ami "\" ni a mo si ___. (This sign "\" is known as ___)
Ami ohun oke
Ami ohun isale
Ami ohun egbe
Ami ohun aarin
Ami "/" ni a mo si ___. (This sign "/" is known as ___)
Ami ohun egbe
Ami ohun aarin
Ami ohun isale
Ami ohun oke
Ami "-" ni a mo si ___. (This sign "-" is known as ___)
Ami ohun oke
Ami ohun egbe
Ami ohun aarin
Ami ohun isale
Iro ___ nikan ni o maa n gba ami ohun sori. (___ letters are the only letters that tone marks are assigned on)
Konsonanti
Silebu
Faweli
Konsonanti asesilebu
__ ati __ ni iro konsonanti aranmupe asesilebu. (__ and __ are the nasal consonants)
T/P
M/N
W/Y
G/GB
Kini "EWI" tumo si? (What does "EWI" mean)
Prose
Title
Poem
Paragraph
Kini "IBUWOLUWE" tumo si? (What's does "IBUWOLUWE" mean)
Signature
Time
Complimentary Greeting
Paragraph
___ ni ona ibanisoro ti a n gba so ero okan wa nipa fifi iwe ranse si elomiiran. (__ is a written communication sent from one party to another)
Aroko
Aroso
Leta kiko
Oro oruko
KUNLE GUN IGI, "Igi" wa nipo ___. (KUNLE GUN IGI, "igi" is positioned as ___)
Oluwa
Abo
Egbon
Nnkan
